Lyrics

[Intro]
It's Dami records baby
Orororororo
[Chorus]
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Ọmọ Je o wa bayii (Je o wa bayii)
O ṣe n ṣe bayii (Je o wa bayii)
O n rin mi (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
[Verse 1]
Bo ṣe n gbe wa naa ni mo n gba lẹnu, ahn ahn
Awọn ọmọ Peckham wọn ma ta lẹnu, ahn ahn
T'ọn ba saṣẹ always working, always setting
Always moving, always sporting
Always popping, always saṣẹ ahn
Are you paying fam? Are you paying fam? Fuck
O ya move move, what the fuck, make you waka well
Ma lọ fọ o ya pana oju kan ko ma fikan riran
O ṣa mọ pe emi gan-an mo le fikan dikan
Ma lọ ba mi faa tori owo mi
O ya tẹ ẹ tẹ, joro mi
Anything to ba fẹ ni maa fun ẹ fun ẹ
Baby jọọ ma sọ fun mi pe o ti rẹ ẹ, rẹ ẹ
Because I'm ready lati o ya press tẹ
Eventhough to ba fun mi laye, maa run ẹ, run ẹ
Abi kẹ ah mo dẹ le fun ẹ, fun ẹ
O ṣa mọ ah man's not hot hmmn ah man's not hot
O ṣa mọ ah man's not hot hmmn ah man's not hot
O ṣa mọ ah man's not hot hmmn ah man's not hot
O ṣa mọ ah man's not hot hmmn ah man's not hot
[Chorus]
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Ọmọ Je o wa bayii (Je o wa bayii)
O ṣe n ṣe bayii (Je o wa bayii)
O n rin mi (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
[Bridge]
Killing the beat Mystro, Mystro, Mystro
[Verse 2]
All my London girls don start to denge pose, denge pose
If you hear the gbẹdu make you bẹrẹ jo, bẹrẹ jo
Mystro leleyi, ijo onijo leleyi eh
If you want to geti pounds geti down eh eh
Owo n bẹ lapo eh, ijo yẹra wo ah
Agege wa ni London lawọn Peckham n yẹra wo
Jo jo let to dey ba mi jo, wọn ba mi jo
Jo jo let to dey jisoro
[Verse 3]
Rekete rekete yan yan yan
Pekele pekele yan yan yan
Wiggle the thing wiggle the thing aunty Ruth dey we gele, yeba
Darami pekete
360 pekele
Eh Mystro leleyi, eh
[Chorus]
Jo Shakira, idi lo rọ to yii
Jo Rahmonu, Jago ma pa mi na
Hmmn ah pepper sneh, shout out to Badoo sneh
Hmmn ah pepper sneh, shout out to Badoo sneh
Hmmn ah they don't know shii, wọn ni pe a n jijo oṣi
Hmmn ah they don't know shii, wọn ni pe a n jijo oṣi
Hmmn ah man's not hot, you know say man's not hot
Hmmn ah man's not hot, you know say man's not hot
Ni gba', ni kọrọ
Ni gbangba ni kọrọ
Gbas gbos ni kọrọ
Ni gbangba ni kọrọ
Ṣigẹ ṣigẹgẹ
B'ọn gbemu ẹ ṣigẹgẹ
Le wọn, le wọn lere
B'ọn yogo ẹ yọ lẹbẹ
Leave am, filẹ beh
Don't touch am filẹ beh
That's my, that's my bae
Don't touch am that's my bae
[Chorus]
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Ọmọ Je o wa bayii (Je o wa bayii)
O ṣe n ṣe bayii (Je o wa bayii)
O n rin mi (Je o wa bayii)
Je o wa bayii (Je o wa bayii)
Je o wa bayii
Written by: Damibliz, Lukmon Damilare Yusuff, Mystro, Naira Marley
instagramSharePathic_arrow_out