Lyrics

Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Onisé akabakibiti Owun l' Olorun To n' bé ki aiye to wà O la na fun awon omo Israeli Ba mi sè ooooohh Ki n ba le sè lé ró Onisé akabakibiti Owun l' Olorun To n' bé ki aiye to wà O la na fun awon omo Israeli Ba mi sè ooooohh Ki n ba le sè lé ró Oooooooo la na fun awon omo Isrealii Ba mi sè oohh Ki n ba le sè lé ró Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Oba ti a ri Ti a mo ododo ré Alagbara to n' gba agbara l' owo alagbara Owun lo l émi ti mo m' mi Owo di Jeriko Oba to ran wa lówo ni gba ti Aba si se Owun l' Oba to Joko si ori ité Ni agbala awon eni Oba Ala anu Oba to pin anu O wo di Jericho AGBARA OLORUN PO Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó Ola na si ori okun Bi oni ja ba l' owun Oja mó O wodi Jericho Iwó a l' o sésé béré ti é Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó Obami alagbara Ola na si ori okun O wodi Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Ehhhhhh... Baba awon alayi ni baba O wo ken bé re ibi ja Ala anu l' eje Oba ti n'gbe ni ibi ti akolegbe Oba to ma wa nigba ti aye o ni si Eeehh Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Agbara Olórun pó Agbara Olórun pó O la na si ori Okun O wo di Jericho Woooooooooooo!
Writer(s): Clement Uwanni Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out