Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
King Sunny Ade
Performer
COMPOSITION & LYRICS
King Sunny Ade
Songwriter
Lyrics
[Chorus]
Gbogbo awọn ayanfẹ ẹ lo ṣe logo
Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awọn ayanfẹ ẹ lo ṣe logo
Oluwa lo pe mi lo yan mi wa sẹ, gbogbo awọn ayanfẹ ẹ lo ṣe logo
Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awọn ayanfẹ ẹ lo ṣe logo
[Verse 1]
Kitakita o ran o, girigiri o ran o
Kitakita o ran o, girigiri o ran o
Ori lo pin ọla ko ni, ori lo n pin ọla ko ni
Ẹda mi pin temi ko mi, ma jẹ n si wọn w'aye
[Verse 2]
Ori mi ma jẹ n si wọn wale aye lasan lasan
Ẹda mi ma jẹ n ṣakobata fun ẹgbẹ mi
Tori kitakita o ran o, girigiri o ran o
Kitakita o ran ọla, girigiri o ran o
Ori lo pin ọla ko ni, ori lo n pin ọla ko ni
Ẹda mi pin temi ko mi, ma jẹ n si wọn w'aye
[Verse 3]
Emi ti gbohun Oluwa to wi pe
Bawa arakunrin o, dide ninu ọgba ajara Oluwa ẹ ko si maa kọrin
Bawa arakunrin o, dide ninu ọgba ajara Oluwa ẹ ko si maa kọrin
Aye le maa ṣata
Written by: King Sunny Ade