Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Adekunle Gold
Adekunle Gold
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Adekunle Gold
Adekunle Gold
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Sess
Sess
Producer

Lyrics

[Verse 1]
Rain or Shine
Money don't buy charisma
Me I just get my vibe
I get my vibe, yo
Oh for life
Gucci no go sell swagger
That thing don't come overnight
It don't come overnight
Emi ni father ṣe jẹjẹ
Baba ni father ṣo mọ?
Emi Don Dada (AG Baby)
Baba ni father ṣo mọ?
[Verse 2]
Juice on ice
Whiskey on the side
Word of advice
Slow your role, boy
[Chorus]
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
Ogororo no be Vodka
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
Coat o ki n ṣẹgbẹ agbada
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
[Verse 3]
It's time to talk the talk
I've been playing this shit safe for long
Mi o ran anybody mọ (Mi o ran anybody mọ)
Pọnmọ n ṣe bi ẹran (Ẹran)
Maruwa n ṣe bi mọto (Mọto)
Eku n ṣe bi ẹkun (Ẹkun)
A ju wọn lọ to ba ya wọn ma gba
Kẹkẹ lo'hun n sare (Sare)
Ere ki lo fẹ sa? (Ere ki lo fe sa?)
To fẹ ju ti mọto (Mọto)
You say you are number one
But na me get the table
[Chorus]
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
Ogororo no be Vodka
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
Coat o ki n ṣẹgbẹ agbada
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
[Refrain]
Juice on ice
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
Whiskey on the side
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
Word of advice
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
[Chorus]
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
Ogororo no be Vodka
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
(Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ)
Coat o ki n ṣẹgbẹ agbada
Kẹlẹgbẹ mẹgbẹ
[Verse 4]
Emi ni father ṣe jẹjẹ
Baba ni father (Ṣo mọ?) Ṣo mọ?
Emi Don Dada, Don Dada
Baba ni father (Ṣo mọ?) Ṣo mọ?
AG baby emi ni father ṣo mọ?
Written by: Adekunle Gold
instagramSharePathic_arrow_out