Music Video

DAMIBLIZ JOWABAYI FT CDQ X MYSTRO X NAIRA MARLEY (Official Video)
Watch DAMIBLIZ JOWABAYI FT CDQ X MYSTRO X NAIRA MARLEY (Official Video) on YouTube

Credits

PERFORMING ARTISTS
Damibliz
Damibliz
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Damibliz
Damibliz
Songwriter

Lyrics

[Intro]
It's Dami records, baby
Ororororo
[Chorus]
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
Ọmọ j'o wa bayii
J'o wa bayii
O ṣe n ṣe bayii
J'o wa bayii
O n rin mi
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
[Verse 1]
Bo ṣ en gbe wa naa ni mo n gba lẹnu, ahn, ahn
Awọn ọmọ Peckham, wọn ma talẹnu ahn, ahn
T'ọn ba saṣẹ, always working
Always siting, always moving, always wanting
Always popping, always saṣẹ ahn
[Verse 2]
Are you paying fam? Are you paying fam? Fuck
O ya move, move, what the fuck
Make you waka well ma lọ fọ
O ya pana oju kan ko ma fikan riran
O ṣa mọ pemi gan-an mo le fikan dikan
Ma lọ ba mi fa a tori owo mi
[Verse 3]
O ya tẹ, tẹ, joro mi
Anything to ba fẹ ni maa fun ẹ, fun ẹ
Baby jọọ ma sọ fun mi po ti rẹ ẹ, rẹ ẹ
Because I'm ready lati apraise ẹ
Eventhough to ba fun mi laye maa run ẹ, run ẹ
Abi kẹ ah mo dẹ le fun ẹ, fun ẹ
[Bridge]
O ṣa mọ, ah, man's not hot, hmmn ah, man's not hot
O ṣa mọ, ah, man's not hot, hmmn ah, man's not hot
O ṣa mọ, ah, man's not hot, hmmn ah, man's not hot
O ṣa mọ, ah, man's not hot, hmmn ah, man's not hot
[Chorus]
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
Ọmọ j'o wa bayii
J'o wa bayii
O ṣe n ṣe bayii
J'o wa bayii
O n rin mi na
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
[Verse 4]
Filẹ, maami ẹ j'o wa bayii
Ki lo de to fine bayii?
Ṣe ibadi yin lo fẹ to yii?
Ọmọ Peckham wa gba iyi
[Verse 5]
Filẹ, o ya kawọ soke bi Halleluyah
Run iya anybody, bi paper suya
Hustle leke gbeleke lai seke
How much I go pay?
Ma fun mi love eke
Are you ready fam?
Jẹ n wọle, ṣi ilẹkun fam
O ma gbonna, so where the fan?
Sanitation, ko lo clear the farm
Woos, gberegbe ti gbebe
Bi ẹja, gẹgẹ ti gẹgẹ
Maami mi o mẹmẹ ti mẹmẹ
Damibliz and CDQ yeah, yeah
[Chorus]
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
Ọmọ j'o wa bayii
J'o wa bayii
O ṣe n ṣe bayii
J'o wa bayii
O n rin mi na
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
[Verse 6]
Killing the beat Mystro, Mystro, Mystro
All my London girls don start to denge pose, denge pose
If you hear the gbẹdu make you bẹrẹ jo, bẹrẹ jo
Mystro leleyii, ijo onijo leleyii
If you want to get the pounds get down eh, eh
[Verse 7]
Owo n bẹ lapo, ijo yẹra wo
Agege wa ni London, lawọn Peckham n yẹra wo
Jojo o, ṣo le ba mi jo
Wọn ba mi jo
Jojo, ṣo le jisoro
[Verse 8]
Rekete, rekete, yan, yan, yan
Pekele, pekele yan, yan, yan
Wiggle the thing, wiggle the thing
Aunty Ruth dey we gele
Darami rekete
Three sixty pekele
Eh Mystro leleyii
[Verse 9]
Jo Shakira, idi lo rọ toyii
Jo Rahmoni, Jago ma pa mi na
Hmmn, ah, pepper sneh, shout out to Badoo sneh
Hmmn, ah, pepper sneh, shout out to Badoo sneh
Hmmn, ah, they don't know shii, wọn ni pe a n jijo oṣi
Hmmn, ah, they don't know shii, wọn ni pe a n jijo oṣi
Hmmn, ah, man's not hot, you know say man's not hot
Hmmn ah man's not hot you know say man's not hot
[Verse 10]
Ni gba', ni kọrọ
Ni gbangba, ni kọrọ
Gbas, gbos, ni kọrọ
Ni gbangba, ni kọrọ
Ṣigẹ, ṣi gẹgẹ
B'ọn gbemu ẹ ṣi gẹgẹ
Le wọn, le wọn lere
B'ọn yogo, ẹ yọ lẹbẹ
Leave am, filẹ bey
Don't touch am filẹ bey
That's my, that's my bae
Don't touch am, that's my bae
[Chorus]
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
Ọmọ j'o wa bayii
J'o wa bayii
O ṣe n ṣe bayii
J'o wa bayii
O n rin mi na
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
J'o wa bayii
Written by: Damibliz, Lukmon Damilare Yusuff, Mystro, Naira Marley
instagramSharePathic_arrow_out