Lyrics
(Mur-Mur-Murderer)
Ijọ buruku lo n'ijọ tuntun
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
Eleduwa, ẹyin l'akọkọ ninu gbogbo nnkan
Kẹ to d'aiye at'ọrun
And that why me I put You first
In everything I do
O ma ma ṣe, Ọlọrun mi, o pọ, o pọ ọ
Ibi t'ọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey
Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'
Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin
Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun rere
Ẹyin to laiye ẹ gb'ohun mi ṣ'aṣẹ pa
I be ọmọ aiye, ẹ duro ti mi, ki n ma ṣe jabọ o
Ikoko la fi ṣe, e gbọdọ fọ o
T'aiye ma fọ igba ikoko mi l'ẹnu
Ay, ti n ba lu n ṣe ni ko ma dun
Ibi t'ọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey
Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'
Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin
Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun rere
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun rere (ay)
Writer(s): Oluwakayode Balogun Abdulqudus
Lyrics powered by www.musixmatch.com