Music Video

Shoday & Ayo Maff - Casablanca (Visualizer)
Watch Shoday & Ayo Maff - Casablanca (Visualizer) on YouTube

Credits

PERFORMING ARTISTS
Shoday
Shoday
Lead Vocals
Ayo Maff
Ayo Maff
Lead Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Shodade Solomon Segun
Shodade Solomon Segun
Songwriter
AYORINDE AYODELE MAFOLUKU
AYORINDE AYODELE MAFOLUKU
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Jhay2unez
Jhay2unez
Producer

Lyrics

(It's The Billion Boy) (Kill dem all) (Ayo, Ayo Maff) Ṣe lo n pe mi zaddy Mo ni, "Baby, what is popping?" Girl, I'm chasing money Ọrọ owo yẹn ṣa lo ba mi If I no press you money, that one no mean say I stingy As ọmọ ọgbọn mo calcu' k'owo ma lọ tan l'ọwọ mi Casablanca mo wọ sọrun (men, I'm looking fresh and classy) Amiri ṣa mo wọ soju (k'aṣiri ma lọ tu) Mo ni, "Balenciaga mo wọ s'ẹsẹ (original, no be fugazi) One million dollar no do me (Ọmọ aiye hustle lọ) Mo ni, "Casablanca mo wọ sọrun" (men, I'm looking fresh and classy) Amiri ṣa mo wọ soju (k'aṣiri ma lọ tu) Mo ni, "Balenciaga mo wọ s'ẹsẹ (original, no be fugazi) One million dollar no do me (Ọmọ aiye hustle lọ, hustle lọ-ọ-ọ) Vanilla Bottega Vanilla Bottega with some Lil Kesh O le jẹ dollar, o le jẹ naira, a wa ma na owo o Ibi ire la ma sọ gba si, k'ọmọ owo ko to gba CC Nothing wey I never see A f'owo m'ọti le ku s'ode So, mo fi Azul to'le Oniyangi ku ro l'ọna mi Ṣo mọ nnkan to wa l'ọkan mi? Ah-ah, steeze no go kill me Valentino l'ori mi Fendi l'ẹsẹ rẹ O le ku nitori mi I blow Hiroshima, Nagasaki Ba mi ṣẹ dollar, Rasaki Balenciaga l'ọrun mi When I dey hustle, ṣo ri mi? Casablanca mo wọ sọrun (men, I'm looking fresh and classy) Amiri ṣa mo wọ soju (k'aṣiri ma lọ tu) Mo ni, "Balenciaga mo wọ s'ẹsẹ (original, no be fugazi) One million dollar no do me (Ọmọ aiye hustle lọ) Mo ni, "Casablanca mo wọ sọrun" (men, I'm looking fresh and classy) Amiri ṣa mo wọ soju (k'aṣiri ma lọ tu) Mo ni, "Balenciaga mo wọ s'ẹsẹ (original, no be fugazi) One million dollar no do me (Ọmọ aiye hustle lọ, hustle lọ-ọ-ọ) K'aṣiri ma lọ tu Original, no be fugazi (Yo-yo-yours truly, BYLINK Mix) Ọmọ aiye hustle lọ, hustle lọ-ọ-ọ (kill dem all)
Writer(s): Mafoluku Ayorinde Ayodele, Shodadesolomon Segun Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out