Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Labisi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Labisi
Songwriter
Lyrics
Daddy mi o, e tobi o
Eleti gbagbara, olowo gbogboro
Atayero bi agogo baba olododo
Awa n se kabiyesi o
Kabiyesi o, fun baba agbalagba
Kabiyesi o, fun baba agbalagba
Kabiyesi o, fun baba agbalagba
Arugbo ojo eh eh
Arugbo ojo oh oh
Olufe okan okan mi
A ji ayo mi o ninu re lati yo o
Written by: Labisi