Credits
PERFORMING ARTISTS
S-Smart
Performer
Trill Xoe
Performer
Azeez Sheriff Atanda
Lead Vocals
COMPOSITION & LYRICS
S-Smart
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Trill Xoe
Producer
Lyrics
[Intro]
And I know that you need to believe
And I know it's not easy to see
But there's something that I've got to face
Wa, wa, waaa
And it's living inside of me
Ahn
And I know that you need to believe
Ah, wa, waaa
And I know it's not easy to see
Jaye lọ daddy ma sun le o
Ọja daddy wa, ah ey
S-Smart again ooo
[Verse 1]
Ahn
Ile-aye yii o nira
Aye lo n mu ọmọ sare
Ile-aye yii o nira
Aye lo n mu ọmọ japa
Ile-aye yii o nira
Aye lo n mu ọmọ sare
Ile-aye yii o nira
Aye lo n mu ọmọ japa
[Verse 2]
Paapapa
Aye lo n mu ọmọ sare
Ah, da, daaaa
Aye lo n mu ọmọ japa
Hm ah da laaa
Aye lon mu ọmọ sare
No papa
Aye lo n mu ọmọ japa
[Verse 3]
Ṣe you know say I no be Usain Bolt?
Ṣe you know say I no be Usain Bolt?
Emi gan-an o sunle mọ
Emi gan-an fẹ gbera
Emi gan-an o sunle mọ
Emi gan-an fẹ gbera
Paapapa
Emi gan-an o sunle mọ
The journey far
Emi gan-an o wale mọ
[Chorus]
As you dey reason your life just dey reason the mullah
Owo ṣe koko
As you dey reason your life just dey reason the mullah
Owo ṣe koko
As you dey reason your life just dey reason the mullah
Owo ṣe koko
As you dey reason your life just dey reason the mullah
Owo ṣe koko
[Verse 4]
K'ọn ma lọ rọ ẹ sẹyin, brother
K'ọn ma lọ gba ẹ sẹyin, sister
K'ọn ma lọ rọ ẹ sẹyin, brother
K'ọn ma lọ gba ẹ sẹyin, sister
Awon ọmọ ghetto mi o sun rara lo ṣe ri p'ọn gbera
Awon ọmọ ghetto mi o sun rara lo ṣe ri p'ọn gbera
Ba ṣe n ṣiṣẹ, la ṣe gbowo, la ṣe n jaye deede
Ba ṣe n ṣiṣẹ, la ṣe gbowo, la ṣe n jaye deede o
Awon ọmọ ghetto mi o sun rara lo ṣe ri p'ọn gbera
[Chorus]
Wa, wa, wa, ey
Owo ṣe koko
I say that kind thing owo ṣe koko
I say wa, wa, wa, ey
Owo ṣe koko
I say that kind thing ọmọ
Owo ṣe koko, ahn ahn
[Outro]
S-Smart again o
Wa, wa, wa, ey
Jaye lọ daddy ma sun le o
Ọja daddy ahn, ahnn
Written by: S-Smart