Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Tolibian
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Abubakar Ottan Abdulmutolib
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Abubakar Ottan Abdulmutolib
Producer
Lyrics
[Chorus]
Saari, saari ti to Musulumi ẹ dide n'lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan-an Ramadan
Oju mi ti ri lọsan-an Ramadan
B'ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹ (Why, why, why)
B'ọn gbomi wa mi o ni le mu o
Agba to lomi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[Verse 1]
Awẹ tan oju tajọsan
Awẹ tan oju tajọsan
Irun ti to ki ẹ lọ bori
Saari ti to jẹ o, ah
Ẹ dide nilẹ o, ẹ lọ se jijẹ o
Ẹ dide nilẹ o, ẹ figbo silẹ o
Ẹ dide nilẹ o, ẹ lo se jijẹ o
Ẹ dide nilẹ o, ẹ figbo silẹ o
[Chorus]
Saari, saari ti to Musulumi ẹ dide n'lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan-an Ramadan
Oju mi ti ri lọsan-an Ramadan
B'ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹ (Why, why, why)
B'ọn gbomi wa mi o ni le mu o
Agba to lomi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[Verse 2]
Ẹ ye fa bakky lọsan-an Ramadan
Ẹ ye gboloṣo lọsan-an Ramadan
Ẹ ma ṣe ṣaṣe ninu Ramadan
O ṣi tun wẹṣẹ ninu Ramadan
Written by: Abubakar Ottan Abdulmutolib