Credits
PERFORMING ARTISTS
Ojo Sunday Alawode
Drums
COMPOSITION & LYRICS
Ojo Sunday Alawode
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Ojo Sunday Alawode
Producer
Lyrics
Iwo Loba
Akobi ninu awon orun o, baba
(You all gonna listen...)
Iba ni nho fi ojo oni se
Kemi to sere
Oba to dami si
Iwo lemi Oma bo
Your excellency daddy
Oro re ni nho ma so
Ti nba ro lilo bibo mi
Mama jo
Ti nba ro lilo bibo mi
Mama jo lo
Iwo Loba
Oba Toni Mi, To Lemi Mi Iwo Loba
Oba Toni Kokoro Aiye Lowo Iwo Loba
Iwo Loba Ah Ah
Oba Toni Mi, To Lemi Mi Iwo Loba
Oba Toni Kokoro Aiye Lowo Iwo Loba
Is there nothing wey God no fit do
laiye yi kosio
Kosi ohun to soro niwaju Eledumare Oba
Oba to da oni kaluku
Oti mo bi ohun afi ire fun
Ada onikaluku lejo
Bi ise owore yio tiso
Oba kon je ni Ilu Kan
Oni Aguntan ati Rakumi
Opo gidi ki Ise eyokon
Alejo de ba Oba lojokon
Oba ori ohun se alejo rara
O nawo mu agbo eni ni eyokon
Onipe kiwon pa fun alejo
Oba pa agbo otun pa alagbo mo
E o ri pe oju aiye leju
Oba to da oni kaluku
Oti mo bi ase se esan fun
Ada oni kaluku lejo bi ise owore yio se so
Iwo Loba
Oba Toni Mi, To Lemi Mi Iwo Loba
Oba Toni Kokoro Aiye Lowo Iwo Loba
Iwo Loba Ah Ah
Oba Toni Mi, To Lemi Mi Iwo Loba
Oba Toni Kokoro Aiye Lowo Iwo Loba
Is there nothing wey God no fit do
laiye yi kosio
Kosi ohun to soro niwaju Eledumare Oba
Written by: Ojo Sunday Alawode