Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Davido
Davido
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Oluwaseyi Christian Akerele
Oluwaseyi Christian Akerele
Composer
David Adeleke
David Adeleke
Songwriter
Kamal Ajiboye
Kamal Ajiboye
Composer
Babalola Oluwagbemiga
Babalola Oluwagbemiga
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Davido
Davido
Producer
Shizzi
Shizzi
Producer

Lyrics

[Intro]
Shizzi, Shizzi
On the beat is Davido
[Chorus]
Ẹ ma da mi duro, yeah
Emi ọmọ baba olowo, olowo
Ani wọn fẹ da mi duro, duro
Ẹ wo wọn, wọn fẹ ba mi nawo, nawo
[Chorus]
Ẹ ma da mi duro, yeah
Emi ọmọ baba olowo, olowo
Ani wọn fẹ da mi duro, duro
E wo wọn, wọn fẹ ba mi nawo, nawo, yeah
[Verse 1]
And on the beat is Davido
And I'm driving all the girls crazy, oh
And on the beat is Davido
And I'm driving all the girls crazy, oh
Wọn gbe
[Verse 2]
Na my money, money o pọ, pọ, pọ, o pọ, pọ, pọ
Ji your money, oh, money, oh, gan-an, gan-an, gan-an, o gan-an, gan-an, gan-an
My money, money o pọ, pọ, pọ, o pọ, pọ, pọ
Ji your money, oh, money, oh, gan-an, gan-an, gan-an, o gan-an, gan-an, gan-an
[Verse 3]
Got my, got my **** B-red in the building
And we counting money, we chilling
Racks on racks until we hit the ceiling
What's up now, now, now?
[Verse 4]
Got my **** B-red in the building
And we counting money, we chilling
Racks on racks until we hit the ceiling
What's up now, now, now?
[Chorus]
Ẹ ma da mi duro, yeah
Emi ọmọ baba olowo, olowo
Ani wọn fẹ da mi duro, duro
Ẹ wo wọn, wọn fẹ ba mi nawo, nawo
[Chorus]
Ẹ ma da mi duro, yeah
Emi ọmọ baba olowo, olowo
Ani wọn fẹ da mi duro, duro
E wo wọn, wọn fẹ ba mi nawo, nawo, yeah
[Verse 5]
And on the beat is Davido
And I'm driving all the girls crazy, oh
And on the beat is Davido
And I'm driving all the girls crazy, oh
Wọn gbe
[Verse 6]
Kulusọ ewe, agbaagba ewe
L'Ọṣun fi n wo ọmọ rẹ ki dokita ko to de
Kulusọ ewe, agbaagba ewe
L'Ọṣun fi n wo ọmọ rẹ ki dokita ko to de
[Verse 7]
Ba mi mujo, mujo
Ijo bBaba Shina Rambo, Rambo
Ani wọn fẹ ba mi mujo, mujo
O mujo ijo Shina Rambo, Rambo, yeah
[Chorus]
Ẹ ma da mi duro, yeah
Emi ọmọ baba olowo, olowo
Ani wọn fẹ da mi duro, duro
Ẹ wo wọn, wọn fẹ ba mi nawo, nawo
[Chorus]
Ẹ ma da mi duro, yeah
Emi ọmọ baba olowo, olowo
Ani wọn fẹ da mi duro, duro
E wo wọn, wọn fẹ ba mi nawo, nawo
[Chorus]
Ẹ ma da mi duro, yeah
Emi ọmọ baba olowo, olowo
Ani wọn fẹ da mi duro, duro
Ẹ wo wọn, wọn fẹ ba mi nawo, nawo
[Verse 8]
And on the beat is Davido
And I'm driving all the girls crazy, oh
And on the beat is Davido
And I'm driving all the girls crazy, oh
[Outro]
Ba mi nawo
Duro, oh
Ba mi nawo
Written by: Babalola Oluwagbemiga Gabriel, Davido, Kamal Ajiboye, Oluwaseyi Christian Akerele
instagramSharePathic_arrow_out