Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Adebesin Khaerat Jumoke
Adebesin Khaerat Jumoke
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Adebesin Khaerat Jumoke
Adebesin Khaerat Jumoke
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Jerryson Production
Jerryson Production
Executive Producer

Lyrics

Idamu o tọ sí mi f'opin sii ki a
Ni'di iṣẹ mi ti mo yan yi ko yẹ mi
Ko ma yẹ silẹ fún mi dakun jọwọ pọn mi le
Iran Alagbede nfi'rin dara ni bo se fe
Agbe na naa ni ebe pelu oko
Abe mu ko mu onikola nlo le wi
Atoke nle Oloun arere ma bo
Ede ti o gbo Kii Shenu mi leo ti gbo
Irori o je nr'orun sun ori ti kun
Ka tun feleyi shey ladura Orin ti ya
Eni fe bee ni ko wi o bi nba shey wi
Tori 'damu o to si mi Iwo naa nko?
B'eyan se ti o yọ nse l'ọkan ẹni a gb'ọgbẹ
Ilu wa mii ṣe ni wọn ma lú f'oní tọhun
Ma j'oju mi tori'wọ lemi gbára le
Ma jẹ k'ẹnu Ọta o ka mi at'ọrẹ bu
L'ẹnu iṣẹ mi ti mo yan ẹni l'ayé
Dami ni are l'asiko k'oto ma pẹ
Ma jẹ nb'ọrọ mi d'orita Ko ma ye mi mọ
Ori wa sin mi lọ s'ibi Ọla Ki ngba're mu
Ibujoko fún Ọlọmọ obinrin o gbẹgẹ
Tori'damu ma ni k'eniyan ma m'amu bọ
Ibujoko mi ma fi dá mi laa mu o
Kongẹ ifẹ mi to ma mọ'tọju mi tan
Lọ́gán ti nba ti mu Ko ma pada tun bọ lọ mọ
Kí nma shileya Ade-ori jọwọ ba mi Shey
Ma ṣe jẹ nko s'ọwọ ọkunrin alagbeda
Ẹ jẹ nki'ra mi ku ayọ ojú mi r'ọdún
Ki ndupẹ ki ntun bẹ'lọhun alekun Ọla
L'ọdun l'osu yi Ọlọhun Ibukun mo fẹ
Lilo bibo mi podi Isho yi mi ka
Ki'le ma yo mi o dakun di mi mu Ọla
Ma fi mi damu ẹbi mi at'Ololufẹ
Ma ma jẹ nko s'ọwọ awọn ajinigbe
Mo ti sa to e Ọlọhun Idamu o da
Odun yi a ya'bo fun mi
Ko ni le koko mo mi
Ori mi a so're fun mi
Oba o ni fina omo Jo mi
Ogun A mu bo gbogbo a pin
Ma ri'dunnu fi saye mi
Ona Ola mi dandan ni k'o la o
Written by: Adebesin Khaerat Jumoke
instagramSharePathic_arrow_out