Lyrics

(M-M-Murderer) (Whoo) As I dey use my six, I keep my seven If you know, you know (oh) Ẹni de'bẹ a mọ o My ex na poverty I'm in love with the money I'm in love with the raba, inside the Ghana, gb'owo yẹn japa oh-oh Mm-yeah, ja'na bi NEPA o (oh-oh) Mm, khaki no be leather o If you carry the ladder go up o To ba d'oke, ma wo o Mm, yeah-yeah Ti wọn ba ni kẹ da'wọ, ọba ni kẹ faagun Some no get hope o, lo ṣe bẹ si lagoon Wọn b'ẹfọn laba', ṣ'omi lo mu ku? Ọbọ ti o ba ja'wo, ko fẹ mọ p'ọbọ n laagun Mm-yeah, laagun, ti igboro ti daru Mm-yeah, laju, k'ọn to la'ri ẹ, laju o Mm-yeah, daamu, k'Ọlọhun ma jẹ a daamu Mo ranti bi mo ṣe fi'le si, lo ṣe jẹ ki n daju Baba, wo ọwọ mi l'oke, wo aye mi l'ode, ah Nigga, when raba no dey, wọn ri mi lote, ah Ah, another day wey me know say nobody go dey, na My way no be your way, na, ori lo gbe, ah-ah, ah Yeah, what's up, my nigga? When things red, aya mi n ja, ah God bless my dealer I'ma soldier, I'ma ninja, ah I don sip tequila, ah Come sight turkey nla, yeah All about my paper, ah-ah Pawọn boy on Insta' Bọbọ na star Ah, ọba ni ka da'wọ, ọba ni ka faagun Some no get hope o, lo ṣe bẹ si lagoon O b'ẹfọn laba', ah, ṣ'omi lo mu ku? Ọbọ ti o ba da'wo, wọn fẹ mọ p'ọbọ n laagun Mm-yeah, laagun, ti igboro ti daru Mm-yeah, laju, k'ọn to la'ri ẹ, laju o Mm-yeah, daamu, k'Ọlọhun ma jẹ a daamu Mo ranti bi mo ṣe fi'le si, lo ṣe jẹ ki n daju Ah, ahn-ahn (daamu) Ah, ahn-ahn (ti igboro ti daru) Mm, who never fuck up, hands in the air Ko s'ẹni to gbọn tan-an (ahn, ahn, daamu, k'Ọlọhun ma jẹ a daamu) (Mo ranti bi mo ṣe fi'le si, lo ṣe jẹ ki n daju, ah)
Writer(s): Abiodun Akintunde, Elijah Olanite, Timileyin Sulaimon Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out