Upcoming Concerts for Anendlessocean
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Anendlessocean
Performer
Ayobami Alli-Hakeem
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Ayobami Alli-Hakeem
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Outgun Onkar
Producer
Lyrics
[Intro]
E le le le le le
Oh-oh-oh
[Verse 1]
Bi mo ṣe n pe Ẹ
O n jẹ mi o
Olukọ, kọ mi o
Ko ṣooṣa, na idolatry o
To n ṣẹgbẹ lẹgbẹ e o
Iwọ ni mo fi ṣaṣọ to n cover mi o
Olugbọ, gbọ mi o, my designer
My pathfinder mi o
Nibi sibi, nibi sakani mi o
[PreChorus]
Yeah, I feel it coming
You even out them odds
Yeah, I feel it racing
You're breaking down my walls
See I know that Your spirit is here with me
O n gbenu mi o
Ko pẹ fun mi
Woriwo, woriwo
[Chorus]
Oṣuba re ooo
Oṣuba re o, woah
Ọjọ lọjọ Ẹ o
Aye laye Ẹ oh
A n bẹri, a n bẹri fun Ẹ
Oṣuba re oo
[Verse 2]
Bi mo ṣe n wo Ẹ
O n dan mi wo
Ara Ẹ kan mi o
My shepherd from the valley o
Ko tọ mi mọ mi, bi Psalm 23 o
Oluṣọ over me ah
My defender mi
Iwọ nikan nikan, ko sẹlomi
Mi o lẹlomi eh ah
[PreChorus]
Yeah, I feel it coming
You even out them odds
Yeah, I feel it racing
You're breaking down my walls
See I know that Your spirit is here with me
O n gbenu mi o
Ko pẹ fun mi
Woriwo, woriwo
[Chorus]
Oṣuba re ooo
Oṣuba re o, woah
Ọjọ lọjọ Ẹ o
Aye laye Ẹ oh
A n bẹri, a n bẹri fun Ẹ
Oṣuba re oo
Written by: Ayobami Alli-Hakeem