Lyrics

Oluwa tobi ni Sioni O si j'oba lori orile-ede Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si ni eru E ni pe gbogbo aye n wariri Ni oruko re Won n k'orin E ti tobi to o Jesu Eh eh Eh eh (Make some noise) Eh eh Eh eh Eh eh Eh eh Eh eh Eh eh Eh eh Ani Oluwa tobi ni Sioni O si j'oba lori orile-ede Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si ni eru Shout hallelujah 'Tori gbogbo aye n wariri Ni oruko re Won n k'orin E ti tobi to o Jesu Awon orun na n s'eleri Won n f'oribale Niwaju ite re o E ti tobi to o Jesu Won ni E ti tobi to o Oooo Oluwa wa E ti tobi to o Jesu Won ni e ti tobi to ooo Oooo Ooo Oluwa wa o E ti tobi to o Jesu Ani gbogbo aye n wariri o Ni oruko re Won n k'orin yeh E ti tobi to o Jesu Awon orun na n s'eleri Won n f'oribale Niwaju ite re o E ti tobi to o Jesu Won ni E ti tobi to o eh Ooooo Oluwa wa o E ti tobi to o Jesu Won ni e ti tobi to o Ooooo Ooo Oluwa wa o E ti tobi to o Jesu Awon oke nla nla won f'oribale Tori Iwo ni ogo ati ola Ju oke nla ikogun won ni lo E ti tobi to o Jesu Iwo ti Olorun Ji dide kuro ninu oku Lati gba wa kuro Ninu ibinu ti'n bo o Eti tobi to o Jesu Iwo Oluwa Olorun To n gbe laarin awon Kerubu T'o po ni ipa ati agbara o E ti tobi to o Jesu Ani gbogbo aye n wariri Ni oruko re Won n k'orin yeh E ti tobi to o Jesu Awon orun na n s'eleri Won n f'oribale Niwaju ite re o E ti tobi to o (Ladies and gentlemen) Jesu (Welcome Pelumi Deborah) Eeeeeeh E ti tobi to Jesu E ti tobi to o Jesu Awon orun n soro ogo Olorun Ofurufu n fi ise re han Ojo de ojo n f'ohun Oru de oru n fi imo han oooo E ti tobi to o Jesu Jesu oooo Jesu Ko si ibi kan tabi ede kan N'ibi ti a ko ti gbo iro wan Iro won la aye ja aaaaah E ti tobi to o (Jesu Jesu Jesu o) Jesu Mo le ko gbogbo eyin mi si Inu apere re Tori o to gb'ojule O to f'eyinti O to f'arati Olodumare E ti tobi to o Jesu Okun ri o o sa Jodani ri o o pada s'eyin Oke kekeke o je duro Niwaju Olodumare E ti tobi to o (Apata Idigbolu) Jesu (Apata Idigbolu) Apata ayeraye Ibi isadi mi Eni ti mo f'eyin ti Ti ko le wo Ti ko le si Ti ko le yi ni'po pada E ti tobi to o Jesu 'Torina Gbogbo aye n wariri Ni oruko re Won n k'orin E ti tobi to o Jesu Awon orun na n s'eleri Won n f'oribale Niwaju ite re E ti tobi to o Jesu Won ni e ti tobi to o Oooo Oluwa wa E ti tobi to o Jesu Won ni e ti tobi to o Ooooo Oluwa wa E ti tobi to o Jesu Bibeli ni ti Oluwa ni ile ati ekun re Aiye, ati awon ti o tedo si Inu re Nitori ti o fi idi re sole lori okun O si gbeka awon isan-omi Tani yio gori oke Oluwa lo? Tabi tani yio duro nibi mimo re? Eniti o ni owo mimo ati aya funfun Eniti ko gbe okan re ka'le soke si asan Ti ko si bura etan Oun ni yio ri ibukun gba Ati ododo l'owo Olorun igbala re Eyi ni iran awon ti n se aferi re Ti n se aferi re Olorun Jakobu E gbe ori yin s'oke, eyin enu-ona Ki a si gbe'yin s'oke, eyin ilekun ayeraye Ki Oba ogo ki o wole wa Tani Oba ogo? Oluwa ti o le ti o l'agbara Oluwa ti o l'agbara ni ogun E gbe ori yin s'oke, eyin enu-ona Ki a si gbe'yin s'oke, eyin ilekun ayeraye Ki Oba ogo ki o wole wa Tani Oba ogo? Oluwa Olorun awon omo ogun Oun na ni Oba ogo (Jeeeesu) Ladies and Gentlemen Welcome Minister BBO Eni ti ite re ki si Eni ti ite re ki sa Oloruko ape-ri-iye Ar'aye-r'orun leekan soso E ti tobi to o Olorun majemu Jesu Araye n bo o Ara orun n bo o Apebo ni o Olodu Omo Are Oloruko ape ri iyanu E ti tobi to o (eeeeeeeeh) Jesu Iwo to koja riri tan See finish ko si l'oro re o Iranlowo eni ti o l'eyan Oba awon oba Olorun mi E ti tobi to o (yeeeeh) Jesu Olorun to n da ase pa Oo gba'se l'owo enikeni ko to p'ase Ta lo dabi ire ninu agbara Olorun majemu Eti tobi to o (Eeeehhh) Jesu Iwo to ma n tun ori alaisuwon se Pelu owo agbara O ro e l'orun Ko ni e l'ara Irorun lo ba de l'odo re Oko mi E ti tobi to o (Yeeeh) Jesu O da aye s'ori omi, omi o je gbe'le aye lo Tani o to ri e tan Olorun majemu Iranlowo eni ti o l'eyan, oko mi E ti tobi to o Asoisotan Olodumare Jesu Olorun ti o ki n rin irin idoti Olorun ta o le fi iwosi re l'ara Oluwa Oluwa wa o Olorun majemu, Olorun mi E ti tobi to o Jesu Ani gbogbo aye n wariri Ni oruko re Won n k'orin E ti tobi to o Jesu Awon orun na n s'eleri Won n f'oribale Niwaju ite re oooo E ti tobi to o Jesu Won ni pe Won ni pe E ba mi juba f'ajunilo E ba n gb'osuba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo (E ba mi o) E ba mi juba f'ajunilo E ba n gb'osuba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo (See see see) Let me teach you the Juba dance Eeeh Eeeh Eeeh Eeeh Eeeh Oya e ba mi o E ba mi juba f'ajunilo E ba n gb'osuba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo (E ba mi e ba mi e ba mi) E ba mi juba f'ajunilo (E ba n gb'osuba) E ba n gb'osuba f'ajunilo (Awon agbagba) E ba mi juba f'ajunilo (merinlelogun won n ju'ba) Won n ju'ba (E maa ju'ba lo) E ba mi juba f'ajunilo (E ba wa ju'ba e ba mi ba mi o) E ba mi juba (Eh) f'ajunilo Oba to n be lori ite titilai (E ba n gb'osuba f'ajunilo) A da'ra po mo awon orun lati keee (E ba mi juba f'ajunilo) Mimo mimo mimo E ba mi juba f'ajunilo (Si Oluwa Olorun Olodumare) E ba mi juba f'ajunilo (A si ite wa le'le) A si aye wa le'le (E ba n gb'osuba f'ajunilo) A gbe s'ori ese re ooooo (E ba mi juba f'ajunilo) Jesu oooo E ba mi juba f'ajunilo BBO ju'ba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo (E ju'ba f'olojukan) Ti n wo egbegberun eniyan (E ba n gb'osuba f'ajunilo) E ju'ba f'oloruko ape ri iye ooo (E ba mi juba f'ajunilo) E ba mi juba f'ajunilo (A ju'ba fun e Mogaji awon alagbara) E ba mi juba f'ajunilo (A ju'ba re oba to n so egan d'ogo) E ba n gb'osuba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo (Eh eh eh eh eh eeeeeh) E ba mi juba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo (Aju'nilo o) E ba n gb'osuba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo E ba mi juba f'ajunilo (tori pe) O wa pel'awon Ero mimo l'ona (O si je o) O si je Imole won L'osan l'oru Ani O wa pel'awon Ero mimo L'ona o O si je Imole won L'osan l'oru Gbogbo aye n wariri Ni oruko re Won n k'orin, (e ti tobi to o) E ti tobi to o Jesu Somebody shout Hallelujah Thank You jesus Thank You jesus Hallelujah Hallelujah Hallelujah Hallelujah thank You Thank you Jesus Awon orun na s'eleri Won n f'oribale Niwaju ite re o E ti tobi to o Jesu Thank You Jesus Hallelujah!
Writer(s): Emmanuel Edunjobi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out