Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Qdot
Qdot
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Fakoya Qudus
Fakoya Qudus
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Solshyne
Solshyne
Producer
Xsmile
Xsmile
Mixing Engineer

Lyrics

[Intro]
Ahhhh
Ih yaaay yeee
Ọmọ ọmọ Mọria
Qdot lorukọ mi o
[PreChorus]
Aye yi kere gan-an bi skirt Ayra Star
O le morin kọ laye n'bi ko ma pada di star
Ayanmẹ pelu kadara no be same thing
Itan ọmọ olowo pẹlu talaka no be same thing
Ẹyin to laye ẹ f'emi naa laye
Me I no be introvert ẹ gbemi naa jade
Me I don try for the game Baba show me which way
[Chorus]
Ẹbẹ la ma boṣika ko jẹ a rọna lọ
Ẹ pe were lọkọ iyawo
Ka ba le mẹran lawo
Ẹyin to laye mo bẹbẹ
Ẹ ma fọwọ bogo mi o irawọ ni mi
Ẹ ṣaanu mother mi
Ọmọde ni mi, ọmọde ni iya mi o
Ẹ ṣaanu mother mi
Atori aye kaye ma fi tọ mi wo
Ẹ ṣaanu mother mi
Ki lanfani aye to ni le jere aye
Ẹ ṣaanu mother mi
Aṣọ ala ni mo wọ e ma tepo saala mi o
Ẹ ṣaanu mother mi
Ogo de ẹmi pin kaye ma fi dan mi wo
Ẹ ṣaanu mother mi
[Verse 1]
Ahhhh, ahh, ahhhh
Yeey eh (Ọmọ ọmọ moria)
Owu alantakun o ṣe n digi
Ṣo mọ t'ọn ba deniyan a rinira
Kaye ma pa kadara da
Ẹ wo banker to n wọkada
Ọmọ pasitọ ti n pawọda
Gbogbo Ashabi kọ lo n ṣa dollar ah ah
Kaye ma pa kadara da
Ẹ wo banker to n wọkada
Ọmọ pasitọ ti n pawọda
Gbogbo Ashabi kọ lo n ṣa dollar ah ah
[PreChorus]
Aye yi kere gan-an bi skirt Ayra Star
O le morin kọ laye n'bi ko ma pada di star
Ayanmẹ pelu kadara no be same thing
Itan ọmọ olowo pẹlu talaka no be same thing
Ẹyin to laye ẹ f'emi naa laye
Me I no be introvert ẹ gbemi naa jade
Me I don try for the game Baba show me which way
[Chorus]
Ẹbẹ la ma boṣika ko jẹ a rọna lọ
Ẹ pe were lọkọ iyawo
Ka ba le mẹran lawo
Ẹyin to laye mo bẹbẹ
Ẹ ma fọwọ bogo mi o irawọ ni mi
Ẹ ṣaanu mother mi
Ọmọde ni mi, ọmọde ni iya mi o
Ẹ ṣaanu mother mi
Atori aye kaye ma fi tọ mi wo
Ẹ ṣaanu mother mi
Ki lanfani aye to ni le jere aye
Ẹ ṣaanu mother mi
Aṣọ ala ni mo wọ e ma tepo saala mi o
Ẹ ṣaanu mother mi
Ogo de ẹmi pin kaye ma fi dan mi wo
Ẹ ṣaanu mother mi
Written by: Fakoya Qudus
instagramSharePathic_arrow_out