Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Young Duu
Young Duu
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Oluwabamishe Lukman Abioro
Oluwabamishe Lukman Abioro
Lyrics
Adeyemi Olanrewaju
Adeyemi Olanrewaju
Composer

Lyrics

[Chorus]
Oyi m o , oyi m o imela (Imela o)
Oyi m o , oyi m o imela
Baba mo rọwọ ẹ o lori aye mi o
Mo riṣẹ ọwọ ẹ lori aye mi o
Emi ati Mọnkẹ o ki la jọ n kẹ o?
Ohun a ni la n kẹ o, ẹ jẹ a jọ maa kẹ o
Oyi m o , oyi m o imela
Oyi m o , oyi m o imela
Baba mo rọwọ ẹ o lori aye mi o
Mo riṣẹ ọwọ ẹ lori aye mi o
Emi ati Mọnkẹ o ki la jọ n kẹ o
Ohun a ni la n kẹ o, ẹ jẹ a jọ maa kẹ o
[Verse 1]
Ahh ma pa mi o, ma pa mi o ninu aye o
Wọn mọ mi o wọn mọ mi o ninu aye o
Ẹ gbe mi o, ẹ gbe mi o ninu aye o
Ẹ gbe mi lọ faraway o
Alignment, enjoyment, arrangement, assignment
Mo tun wa confident, mo tun wa confident
Ọta le mi, wọn le mi, wọn o le ba mi o (Wọn o le ba mi o)
Wọn wa mi o, wọn wa mi, wọn o le mu mi o (Le mu mi o)
Wọn wa mi, wọn wa mi, wọn o le ri mi o
[Chorus]
Baba mo rọwọ ẹ o lori aye mi o
Mo riṣẹ ọwọ ẹ lori aye mi o
Emi ati Mọnkẹ o ki la jọ n kẹ o?
Ohun a ni la n kẹ o, ẹ jẹ a jọ maa kẹ
[Outro]
Baba mo rọwọ ẹ o lori aye mi o
Mo riṣẹ ọwọ ẹ lori aye mi o
Emi ati Mọnkẹ o ki la jọ n kẹ o?
Ohun a ni la n kẹ o, ẹ jẹ a jọ maa kẹ
Written by: Adeyemi Olanrewaju, Oluwabamishe Lukman Abioro
instagramSharePathic_arrow_out