Similar Songs
Lyrics
Sari
Sari tito Muslim e dide nle kejeun o
Ehn losan ramadan
Oju mi tiri losan ramadan
Bon gbon je wa mio ni le je
Bon gbomi wa mio ni le mu o
Agba to lo min ninu O kin pariwo moti n gba awe o
Awe atan oju ati ajosan
Awe atan oju ati ajosan
Irun tito ki elo bori
Saari ti to je o ah
Edie nile Elo se jije
Edide nile E figbo sile
Edie nile o Elo se jije
Edide nile o E figbo sile
Sari, sari tito Muslim e dide nle kejeun o
Ehn losan ramadan
Oju mi tiri losan ramadan
Bon gbon je wa mio ni le je
Bon gbomi wa mio ni le mu o
Agba to lo min ninu o kin pariwo moti n gba awe o
Èyè fa baki losan ramadan
Èyé gbe olosho losan Ramadan
Emashey sha ishe ninu Ramadan
Oshi tun we oshe ninu Ramadan
Writer(s): Abubakar Abdulmutolib Ottan
Lyrics powered by www.musixmatch.com