Music Video

Tope Alabi - KABI O OSI (Spontaneous Song)- Video
Watch Tope Alabi - KABI O OSI (Spontaneous Song)- Video on YouTube

Credits

PERFORMING ARTISTS
Ty Bello
Ty Bello
Performer
Tope Alabi
Tope Alabi
Performer
Adejumoke Oshoboke
Adejumoke Oshoboke
Background Vocals
George Alao
George Alao
Keyboards
COMPOSITION & LYRICS
Tope Alabi
Tope Alabi
Songwriter
Ty Bello
Ty Bello
Arranger
George Alao
George Alao
Arranger
Josh Keyz
Josh Keyz
Arranger
PRODUCTION & ENGINEERING
Ty Bello
Ty Bello
Producer
David Joshua for Ideal Concept Solutions
David Joshua for Ideal Concept Solutions
Recording Engineer
George Alao
George Alao
Producer
Wole Adesanya
Wole Adesanya
Mixing Engineer

Lyrics

Kabi o osi
Kabi o osi
Arugbo ojo, ad'agba ma tepa
Kabi o osi
We worship you, kabi o osi
We worship you, kabi o osi
Arugbo ojo, ad'agba ma tepa
Kabi o osi
Won o mu o lo l'edi ki won fi ewe akoko le o lori n'be
Ko s'awon to gbinmo po lati so pe e je a fi joba
Ab'awon wo lo duro tan ni won a ma joba n'idile won gan
Awon wo lo fi o je t'o fi'n j'oba kon da wa l'ohun
Ta leni isaju to mu o wa s'inu orun
Ta leni to fa o ni tete wonu aye pe ko wa d'aye
Oya, k'enikan fi baba tabi iya re han wa o, aare
Kabi o osi
Arugbo ojo ad'agba ma tepa l'oruko re
Kabi o osi
O l'oyun ara re, obi'ra e, o s'ora e lo'ko
Ipa ti o se bi l'eere, eni ti o se yi pada
Ite re l'orun kii si onipo ta o le ro l'oye
Arugbo ojo ni o, ad'agba ma tepa o
Ehh, iwo ni ka bi o osi
Riru omi okun po, nje won o ni dake to ba l'oto
Iyanrin nla tun wa, to ba k'aye tan se won o ni pare
Igba t'ohun gbogbo ta ko ba di wiwo pale iwo ni o ku o
Arugbo ojo, onilu a lu la'torun o
Ehh eh eh eh eh kabi o osi
O ko d'aye eru b'aye pe kilo fe wa ninu ohun
Igba to da aye tan, o m'ohungbogbo s'aye e kon ma j'oko won
O ti n gbe'bikan ki o to ko orun aare nla ni o, o se tu
Ailetuwo adahunro adahunso Olunkankun ni o
Arugbo ojo, ad'agba ma tepa ooo
Iwo ni ka bi o osi
Omomo to mo'yun sinu alaboyun to f'ori f'eti f'enu si
O f'imu o f'ohungbogbo sibe e, o de d'igba kan o bi
Se bi bo ba pe ki mimi o ma mi, tani n jebe o
Iwo ni kabi o osi
Agbara re po o ju t'ara lo, iwo lo da ara
Okun re po ko de le pin, oni'mi iye
Iwo lo mimi'ye si amo lasan to pada wa d'eniyan
Ehh eh eh eh kabi o osi
Oba ti'n f'oba je, oba to le r'oba l'oye to le ni ko ma mi mo
Oba ta o gbodo bi bo ba se'n sise owo re si
Ojo n'ro oye n'fun be l'orun ran l'asiko re o
Agbara re po o
Kabi o osi
Mo ni kabi o osi
Kabi o osi
Kabi o osi
Alagbada ina, alawotele oorun
Eh eh eh kabi o osi
Written by: Tope Alabi
instagramSharePathic_arrow_out