Credits
PERFORMING ARTISTS
Kenny Peters
Performer
BBO
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olayiwola Kehinde Peter
Songwriter
Lyrics
[Chorus]
Mo moore mo moore mo moore Ọlọhun
Mo moore mo moore mo moore Ọlọhun
Mo moore mo moore Ọlọhun mi
Mo moore mo moore
Mo moore mo moore Ọlọhun
O ti ṣe, Baba loke o ti ṣe o
[Verse 1]
Gbogbo igba lo n ṣa tọju mi
O tun kẹ mi bi ọmọ ikoko
Certificate mi gan-an gan-an ko le ṣe
Nipa mimọyan mi o ma mọyan rara
Iwọ lolumọ to da oluranlọwọ
Iba rẹ mọ re o Baba
[Verse 2]
Gbogbo igba lo n ṣa tọju mi
O tun kẹ mi bi ọmọ ikoko
Certificate mi gan-an gan-an ko le ṣe
Nipa mimọyan mi o ma mọyan rara
Iwọ lolumọ to da oluranlọwọ
Iba rẹ mọ re o Baba
[Verse 3]
Emi o ni ya alaimore
Emi o ni ya alaimore
Gbogbo igba lo n ṣa tọju mi
O tun kẹ mi bi ọmọ ikoko
Certificate mi gan-an gan-an ko le ṣe
Nipa mimọyan mi o ma mọyan rara
Iwọ lolumọ to da oluranlọwọ
Iba rẹ mọ re o Baba
[Verse 4]
Iba rẹ ma re alatilẹyin mi (Iba rẹ ma re oo Baba)
Iba rẹ ma re oo Olodumare (Iba rẹ ma re oo Baba)
Iba rẹ ma re arannibanilọ (Iba rẹ ma re oo Baba)
Iba rẹ ma re Mọgaji awọn alagbara (Iba rẹ ma re oo Baba)
Ẹni to n sọ ẹgan di ogo, ẹni to n tun ori alaisunwọn ṣe iba rẹ ma re (Iba rẹ ma re oo Baba)
Ẹni to fu ọlẹ ni agbara, ẹni to fun ẹda lọrọ sọ, iba rẹ ma re (Iba rẹ ma re oo Baba)
Ọlọhun Adeboye Iba rẹ ma re o
Iba rẹ ma re o (Iba rẹ ma re oo Baba)
Iba rẹ ma re o (Iba rẹ ma re oo Baba)
Ọba adanimagbagbe ẹni, iba rẹ ma re o Baba
Ọba adanimagbagbe ẹni nisẹ o (Iba rẹ ma re oo Baba)
Ọba ti o mẹni toju n kan, ẹni to kan lo maa da lohun (Iba rẹ ma re oo Baba)
Awọn agbaagba mẹrindinlogun wọn n joba rẹ lode ọrun Ọlọhun majẹmu (Iba rẹ ma re oo Baba)
Iwọ lo ma n gbogo fọlẹ ta wa Ọlọhun majẹmu (Iba rẹ ma re oo Baba)
N o maa yin ọ titi aye mi Ọlọhun, Ọlọhun (Iba rẹ ma re oo Baba)
Olupese, oludaabobob, Ọlọhun, Ọlọhun, Ọlọhun (Iba rẹ ma re oo Baba)
Ọba mimọ to wuwa mimọ lasiko mimọ o (Iba rẹ ma re oo Baba)
Ọba ẹrin nla, Ọba ẹrin nla, Ọba ẹrin nla, oh oh, oh oh
[Verse 5]
Ah, o ti ṣe, o ti ṣe, Ba mi loke o ti ṣe
Mo moore, ah mo moore, mo moore o Ọlọhun
Emi Kehinde ọmọ Olayiwola o mo moore o Ọlọhun
Iwọ nkọ ọmọ Bakare o, BBO
O ti ṣe, o ti ṣe o
Ohun aye lero pe ko le ṣe e ṣe o fọwọ agbara ṣe fun mi yo oh
O ṣe nirọrun
Ohun to b pa mi lẹkun o ti ṣe
O ti ṣe o
[Outro]
Mo moore, mo moore
O ti ṣe, o ti ṣe, Ba mi loke o ti ṣe
Written by: Olayiwola Kehinde Peter