Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Reekado Banks
Reekado Banks
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Reekado Banks
Reekado Banks
Songwriter
Jaya David Olaoluwa
Jaya David Olaoluwa
Songwriter
Olajide Oladapo David
Olajide Oladapo David
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Del B
Del B
Producer

Lyrics

[Intro]
Duru mọ mi
Ọmọ duru mọ mi tonight
Jẹ ka do something tonight
[Chorus]
Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco
O fakọsi, o wọ Fendi, mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn ah
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi, mi o wọ Kito
[Verse 1]
Wọn ranju, wọn ranju
Nibo lo ti wa, nibo lo ti wa?
Won a gbele ma gbọ, wọn a gbele ma gba
Guarantee, guarantee
Beautiful, o tun n ṣana
Mmm-mmm
[PreChorus]
Bad belle enemies, won't let me drink water drop cup, eh
Wọn tun ti n sọrọ mi
Put it inside your tea make you drink am oo
Captivating, captivating (Mo gbe)
Bad girl, ọmọ did not come to play
She no come to play
Uh awon l'ọn n ṣere
[Chorus]
Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco
O fakọsi, o wọ Fendi, mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn ah
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi, mi o wọ Kito
[Verse 2]
No think am o yẹ k'ọn ti mọ
O n lọ, o n lọ, o ti n lọ
Nibi bayi
Ilẹ o ki i ṣu
Mi o dẹ ti fẹ sun
[PreChorus]
Bad belle enemies, won't let me drink water drop cup, eh
Wọn tun ti n sọrọ mi
Put it inside your tea make you drink am oo
Captivating, captivating (Mo gbe)
Bad girl, ọmọ did not come to play
She no come to play
Ọmọ emi gan-an o wa ṣere
[Chorus]
Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco
O fakọsi, o wọ Fendi, mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn ah
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi, mi o wọ Kito
[Verse 3]
Boya ka fagbo bi Fela
Awọn kan fa cigar
Wọn n jo wọn n bend down
Ẹla oju kan ẹla oh
[Outro]
Wọn tun fa cigar
Ẹla oju kan ẹla
Wọn n jo wọn n bend down
Wọn tun fa cigar
O n jo wọn ẹla
Ẹla oju kan ẹla
Written by: Ayoleyi Hanniel Solomon T, Ayoleyi Hanniel Solomon t/as Reekado Banks, Jaya David Olaoluwa, Olajide Oladapo David
instagramSharePathic_arrow_out