Top Songs By Yungtee
Similar Songs
Credits
COMPOSITION & LYRICS
Adegoke Olatunde
Songwriter
Alade Quwam
Songwriter
Lyrics
[Intro]
DJ Que dangbana DJ
I'm the unusual being aya ya ya
Ọmọọla, ah
[Verse 1]
She look so fine look so good
Girl so fine so cool
Tanmọsoko
Ẹ ti rogo
[Verse 2]
Shawty look so fresh look so cool
Your body so bad our road
You be government
Show your logo
Your body barrier
How body Maria
O tojọ mẹta ta rira
Sexy Melanin bọ sita
[Verse 3]
I dey knack like ah shoe maker
Prison breaker, undertaker
Always on the go for da paper
Sky scraper, land scraper
Ẹni a ba laba la n pe baba
Ọmọ t'ọn ti do pa to n gara
To ti ko sọwọ adonipa
Oyin ko sọwọ wọn d'Oyin pa
Pussy wide pussy ya
Nurse ja nurse ya
O ti ka loju bi ti carnival
Me and you not same calliber
[Verse 4]
Lootọ lo dun lọmọ obinrin
Bi puna ẹ ṣe fẹ to aje mi o yiri
O ti waye o raye
But o mọ b'ọn ṣe n ṣe laye
Laide ṣo raye Taye
Lọmọ ti mo ro pe maa ba n'le
A ṣo sa n'le ni ko dẹ la a ye mi
Mo ko si kọnga emi laye mi
Mo ti gbọ story kan nipa giver kan
Ọmọ t'ọn sọ a ṣe Taye ni
[Bridge]
Bukky
Bukky (She a pretty girl)
Bukky
E mẹlo mo pe ẹ Bukky?
Obo ẹ jin
O dẹ cheat
Obo ẹ stink
You a shit
[Verse 5]
A le ni o jeni ko jọla
Ko pounds ko dollar
Korin dowo ko dọla
Do-re -mi-fa-so-la
Ina n jo, oh ara adugbo
Tewurẹ ba wọle o dẹran amuso
[Verse 6]
Mi o fẹ rejabọ mo fẹ ṣana
Mo fẹ dele mo fẹ bana
Ọmọ ẹlẹ ti mo gbe yii dangbana
O fẹ fi ijabe ma gunyan
O n ṣebi Yanyan
O n long cap, o n talk jack shit
[Verse 7]
She a pretty girl
Mo lo ma gbadun mi
O pe mi lorukọ
O tun da cord bo mi
Your body barrier
How body Maria?
O tojẹ mẹta ta rira
Sexy Melanin bọ sita
[Verse 8]
She look so nice look so good
Girl so fine so cool
Tanmọsoko
Yeh mo ti rogo
Mo rogo
[Outro]
Dakẹ ẹnu iya ẹ
Were tun n sọrọ
Written by: Adegoke Olatunde, Alade Quwam