Top Songs By Lanre Teriba
Similar Songs
Credits
COMPOSITION & LYRICS
Lanre Teriba
Songwriter
Lyrics
Olódùmarè wá mú inú mi dùn
Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje
Olódùmarè wá mú inú mi dùn
Àwọn tí mo fò'kan to o wọn ba mi ninuje
Torí mi ó l'ẹni tí mo fe oppress n'ile aiye
Mi ó dé l'eyán tí mo fe buga fún
As I no dey here for competition
If you say you pass me no problem
Me too I pass somebody
B'opé b'oyá o ni ile aiye congratulation akárí gbogbo wa
Written by: Lanre Teriba