Top Songs By Yan Yan
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Yan Yan
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Yan Yan
Songwriter
Lyrics
[Intro]
Yan Yan, Yan Yan
Worry season
Worry season, worry season
[Verse 1]
Them say buzz me up for business only
Paste all drops for instant cash out
Don’t dm for rubbish talking
Igi ewedu o ni wo pa wa o
[Verse 2]
The Lord is my Shepherd I shall not want (Pẹlẹ)
Jokoo sibẹ nigba yẹn ko ma bomb
Steady income a day money boys ti gbowo lọ
IPhone oloju mẹta ti jade
Ṣade ba doko lọ
[Verse 3]
Wọn ti tunṣeẹ pin ọka ti fo (Fo)
Ghana o nibi re
Wo na sapa wo na sapa must to go (Must to go)
Ijo ọpẹ l'awa fẹ jo
You can keep your igbo
Colorado two puff ti to (O ti to)
Ṣe na like this we go de dey?
Emi naa fẹ level up
Gucci yẹn wọn I go like to wọ ọ
[Verse 4]
Tunde jẹ a leg ẹ (Jẹ a leg ẹ)
Ẹni kọle lo ma fence ẹ
O sure pe ti iṣu yẹn ba jina tan
Awọn kan ma yọ fork a maa shenk ẹ (A maa shenk ẹ)
[Verse 5]
Wọn ni iru mi kọ
Them say my flows na premature
Ki n to le join squad wọn ma fill form ṣiọ
Wọn ni ki n ṣe imi ki n gba award
Wọn gbe pot concoction wọn lọ
Baba ba fun mi ni adogan jollof (Praise the Lord)
[Verse 6]
As ọmọ oro mi o ni lelẹ
O sure pe maa ri label
Ibi maa de ibi maa de, mo maa debẹ
Coco Chicago mo gbudọ ge nbẹ
Ana watch o to ba pe ẹ ni blood ko jp
Na cain kill abel
[Verse 7]
Ajeh I no go fall
Like Sars way see Yahoo boi to n gbowo lọ
I go cock my gun, cock my gun
Lamba ta mu pastor gbe body ninu church
Mi o dẹ le gbagbe 99 orientations
Ruggedity kan
[Verse 8]
Fine wọn ni khalifa ti gbera
Na my guy we gather dey
Jẹ n burst ẹ up at all at all na hin bad pass na
Nigba ti ọmọ iya mi maa reply
O ni Nasty me self no guide
But mo le help to bani cc tabi bank sa
[Verse 9]
O ti di warnnkan ti sup everybody sọ yahoo di plump
Ọmọ Iyawo
O ti dogun nsin o
Ẹ ba mi kilọ fun ọmọ olobo Amazon wazo
Ti pussy ẹ o ba ni lock
Ọgbẹni tete lọ ra key si o
[Verse 10]
Weed is my friend
Money na first
Ki n ma i ti rowo eti maa na
Oju maa ran oko ma le
Igbẹ maa rọ (Igbẹ ma rọ)
[Verse 11]
Ti mo ti bomb offer up
Mo wa ti n sẹmi de inbox
Ba n gba Makati l'ago agbawo ship and shop
[Verse 12]
Steal from devil and run to God
Yahoo ni babalawo
O fẹ di boss
Lọ sọ ọ di plus
T'ẹsẹ ile bọ ọ
Ko to ti bọ ọ o jẹ tan torch
To ba dẹ n ṣagbo ko maa watch
O ti pẹ ti iṣan meji t'awa ti cut
[Verse 13]
Shocking news
Few days ago mo ma ba post
Mo ma ri Lil Frosh
O take selfie pẹlu Quavo
Emi naa o kere mi o dẹ yọjo
O nidii ta fi k'ọwọko
K'ọn ma wa surprise ti ba jẹ knuckle Badoo
[Verse 14]
Awọn olowo ni YanYan ba to
Awọn ọlọrọ mo ba fo (Mo ba fo)
Yellow la wa fi ṣe anko (Fi ṣe anko)
Omi gutter la wa fi ṣe Coke
Aṣiri lo n bo actor lo n ṣiṣẹ bro
Ki lo kan Boss?
[Verse 15]
No long cap I rest my case
Wo table ti shake
2020 a maa pa iya yin pẹlu savage
I repeat again
Wo table ti shake
To ba dẹ bẹ lẹyin ko jẹ home and away
Written by: Yan Yan