Top Songs By Naira Marley
Credits
PERFORMING ARTISTS
Naira Marley
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Leonard Opina
Composer
Azeez Fashola
Lyrics
PRODUCTION & ENGINEERING
Leonard Opina
Producer
Lyrics
[Intro]
Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians
Gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ
Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians
MD, MD, MD, MD yii bad oh
[Verse 1]
Wọn ni ẹ n wa Lyta (Wọn ni ẹ n wa Lyta), Lyta wa ni YBNL (Lyta wa ni YBNL)
Wọn ni ẹ n wa lamba (Wọn ni ẹ n wa lamba), lamba wa lọwọ NM (Lamba wa lọwọ NM)
Wọn lẹ n wadii (Wọn lẹ n wadii), Souti lo ni idi mehn! (Souti lo ni idi mehn!)
Ẹ wodi (Ẹ wodi), wọn travel lọ ṣedi yẹn (Travel lọ ṣedi yẹn)
[Chorus]
A ṣo pọ to yii (A ṣo pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
O pọ to yii (O pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
A ṣo pọ to yii (A ṣo pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
O pọ to yii (O pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
[Verse 2]
Awọn omo soak away (Awọn omo soak away), wọn ni ki n suck am well (Wọn ni ki n suck am well)
If I go the club (If I go the club), mo ma take away (Mo ma take away)
O fẹ ka mi o (O fẹ ka mi), mo ya look away (Mo ya look away)
Ọmọ ase, o lọ n duro de giveaway (Kuo n'bẹ)
Gbẹsẹ na (Gbẹsẹ na), a bo ti ni injury (A bo ti ni injury)
Jijo mi o (Jijo mi), give me five minutes like Indomie (Indomie)
O n wo mi o (O n wo mi o), o da bi pe o fẹ do mi o (O da bi pe o fẹ do mi o)
Ba n mu igan mi o (Ba n mu igan), ọmọ ase, ba n mu gbo mi (Ba n mu gbo mi)
Aboki wire o ni gan mọna (O ni gan mọna)
Inshallahu, o ma rowo na (O ma rowo na)
Pound Sterling lo fi n sanwo mi (Lo fi n sanwo mi)
Dollar dollar lo fi n sanwo mi (Lo fi n sanwo mi)
[Verse 3]
Ko sogun aiku, iku lo gara ju
Were to ṣogun aiku fun gan-an, to ba ku bawo lo ṣe fe gba refund?
Ki lo fẹ mu, o ni ki n fun oun ni Coke, cokeka!
Mo gbe dealer mi, oun sniff, emi gbegbo sẹnu, ganja!
O fẹ gbẹnu sẹnu, baby girl can you gbẹnu si tobi? Go down
O fẹ gbẹnu sẹnu, baby girl can you gbẹnu si tobi?
[Verse 4]
Aya kiki, bi obo tiger
Sexy girl, jẹ ki n gbori si ẹ laya
Papapa ẹ bi ti sugar, mo ti fẹ da, obo yẹn dun bi sugar
Da ki n to da, o ni ki n jẹ koun mọ ki n to da
La nnkan to fẹ la, jẹ k'ọn mọ pe ile-aye la bọla
[Chorus]
A ṣo pọ to yii (A ṣo pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
O pọ to yii (O pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
A ṣo pọ to yii (A ṣo pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
O pọ to yii (O pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
[Verse 5]
Ẹṣẹ to gbeyan ṣubu (Ẹṣẹ to gbeyan ṣubu), o fẹ dide o tun ṣubu (O fẹ dide o tun ṣubu)
Toju ti wu (Toju ti wu), Ọlọhun ma ma jẹ a ṣoriibu (Ọlọhun ma ma jẹ a ṣoriibu)
O lọ gba soldier leti, o sọ pe oun o mọ ọn mọ
N'gba ti soldier o wọ uniform, wọn ki i gbẹjọ soldier lọ si court
Yebariba (Yebariba), samboribo
Wọn mọ mi, ni Mushin d'Eko
Wọn mọ mi l'Ojora dọja Oyingbo
Ere ki laja n bẹkun ṣe? (Ere ki laja n bẹkun ṣe?)
Ki l'ọn tun ni Marley ṣe? (Ki l'ọn tun ni Marley ṣe?)
I'm from Peckham by the way
Bad energy please stay far away
[Chorus]
A ṣo pọ to yii (A ṣo pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
O pọ to yii (O pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
A ṣo pọ to yii (A ṣo pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
O pọ to yii (O pọ to yii)
Aṣọ lẹ fi bo o (Aṣọ lẹ fi bo o)
[Outro]
Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians
Gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ
Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians
MD, MD, MD, MD yii bad oh
Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians
Gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ, gbẹsẹ
Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians, Marlians
MD, MD, MD, MD yii bad oh
Written by: Azeez Fashola, Leonard Opina