Lyrics

[Intro]
Ọmọ eniyan feti si
Ọrọ agba, bi o ṣẹ lowurọ a ṣẹ lọwọ alẹ
[Verse 1]
Bo wu ko pẹ titi, iya aye wa o n bọ wa dopin
Aimọla ẹda lo n mu ẹda ṣaniyan ra
Ọlọrun ti ṣeleri, ọrọ Baba ko ni yẹ
Ainigbagbọ lo mu ẹda raropin
Bi okun n fo ti ọsa n sa
Otitọ wa laaye
Igbagbọ ni orisun ohun gbogbo
[Chorus]
Oh hu hu hu, aye yii ko ma le
Aye o le fun ẹni to nigbagbọ p'aye o le
Oh hu hu hu, aye yii ko ma le o
Aye o le fun ẹni to nigbagbọ p'aye o le
Hu hu hu, aye yii ko ma le
Aye o le fun ẹni to nigbagbọ p'aye o le
Oh hu hu hu, aye yii ko ma le o
Aye o le fun ẹni to nigbagbọ p'aye o le
[Verse 2]
Onisuuru, apẹkotojẹ, ko ni jẹbajẹ
Ai ma ni suuru lo n mu are ẹni bọ wa dẹbi
F'oju ire wo mi ọrẹ, k'Oluwa le foju ire wo ẹ
Abiku ti d'abiye ninu aye mi
Onisuuru, apẹkotojẹ, ko ni jẹbajẹ
Ai ma ni suuru lo n mu are ẹni bọ wa dẹbi
F'oju ire wo mi ọrẹ, k'Oluwa le foju ire wo ẹ
Abiku ti d'abiye ninu aye mi
[Chorus]
Oh hu hu hu, aye yii ko ma le
Aye o le fun ẹni to nigbagbọ p'aye o le
Oh hu hu hu, aye yii ko ma le o
Aye o le fun ẹni to nigbagbọ p'aye o le
Hu hu hu, aye yii ko ma le
Aye o le fun ẹni to nigbagbọ p'aye o le
Oh hu hu hu, aye yii ko ma le o
Aye o le fun ẹni to nigbagbọ p'aye o le
[Refrain]
Ha ha ha, aye rẹ ko ma ni le
Ha ha ha, to ba b'Ọlọrun rin, o ṣoriire
Ha ha ha, aye rẹ ko ma ni le
Ha ha ha, to ba b'Ọlọrun rin, o ṣoriire
Ha ha ha, aye rẹ ko ma ni le
Ha ha ha, to ba b'Ọlọrun rin, o ṣoriire
Ha ha ha, aye rẹ ko ma ni le
Ha ha ha, to ba b'Ọlọrun rin, o ṣoriire
[Outro]
Bo wu ko pẹ titi, iya aye wa o n bọ wa dopin
Written by: Infinity
instagramSharePathic_arrow_out