Top Songs By C&S Youth Europe
Similar Songs
Credits
COMPOSITION & LYRICS
C&S Hymn Book Orin Inu Iwe
Songwriter
Lyrics
Otito Jesu f'agbara wenumo
Awe o ninu eje odagutan
Iwo a gbekele ore ofe re
A we o ninu' eje
Awe o ninu eje
Ninu eje Odagutan fun okan
Aso re a funfun o si mo laulau
Awe o ninu eje Odagutan
O mba Olugbala rin lojo jumo
A we o ninu eje Odagutan
O simi le Eniti a kan mo gi
A we o ninu eje Odagutan
Awe o ninu eje
Ninu eje Odagutan fun okan
Aso re a funfun o si mo laulau
Awe o ninu eje Odagutan
Aso re funfun lati pade Oluwa
O mo lau ninu eje Odagutan
Okan re mura fun le didan loke
Awe o ninu eje Odagutan
Awe o ninu eje
Ninu eje Odagutan fun okan
Aso re a funfun o si mo laulau
Awe o ninu eje Odagutan
Bo ewu eri ese si apa kan
Ko si we ninu eje Odagutan
Isun kan nsan fun gbogbo okan aimo
Jo lo we ninu eje Odagutan
Awe o ninu eje
Ninu eje Odagutan fun okan
Aso re a funfun o si mo laulau
Awe o ninu eje Odagutan
Written by: C&S Hymn Book Orin Inu Iwe