Similar Songs
Lyrics
Iji ra ale, aleka malaika (aleka malaika)
Ijimi ma serifu Malaika mi
Qdot lórúkọ mí
Bàbá lókè, má fí mí sí one corner
Àgbà dé k'ọn tó gb'ohùn Rolling Dollar
Má ṣe mí l'Aboki oníṣẹ́
Bàbá, dàkún, ṣé mí lọmọ aláṣelà
Ṣébí alapata lo lọrun ẹran
Má sọ pé ó dán ìgbàgbọ mí wo
K'ayé má bá tú mí l'aṣọ wo
Ọmọ Adeboye ó gbọdọ wọ ẹkùn ègùn
Ọmọ alapata ó gbọdọ jẹ egungun
Ṣé mí ní daroṣa, má ṣe mí l'alakisa
Ọlọrun àwọn Ọlọrun
Mó tí gbé Bíbélì, gbé Qurani (mo gbé oh)
Mó tí fi tí Késárì fún Késárì (fún Késárì)
Mó tí lọ church, mó tí lọ mosa'asi
Àgbàlagbà mo mí dáa lọ yí
Ẹlẹdà má sún (ẹlẹda mí má sún)
Ẹlẹda má sún (ẹlẹda má sún)
Ẹlẹda mí má sún (whoa)
Mó gbàgbọ pé ọmọ Ọlọrun ní Jésù
Mó gbàgbọ pé òjíṣẹ́ rẹ l'Anọbi (sallallahu 'alayhi wa sallam)
Ọlọrun ó ṣe'bì èèyàn lo ń ṣe'ka
T'ayé bà bínú wọn má ní kí Eyimba na Barça pàá oh
Qudus ó mọ pé ogún láyé oh
Ń bá rà ìbọn, ń bá rà'dá
Àwọn tẹ gbàyé fún, k'ọn ṣ'ojú àyé
K'ọn ma f'áyé mí t'afala
Àdàbà tí ko lé fo mọ, oh-ohh
Ọmọ aráyé lo tún dáa
Mó tí gbé Bíbélì, gbé Qurani
Mó tí fi tí Késárì fún Késárì
Mó tí lọ church, mó tí lọ mosa'asi
Àgbàlagbà mo mí dáa lọ yí
Ẹlẹda má sún (ara eli Mikail)
Ẹlẹda má sún (ara 'ba malaika fali mi)
Ẹlẹda mí má sún (e li kulu modá bara n kadu 'lifa)
Ẹlẹda má sún (ẹrí ń bẹ lókè Agelu)
Ẹlẹda mí má sún (sata ta ulehu)
Ẹlẹda má sún (orí mí, jọọ-)
Mà jẹ ń d'àgbàya kí n tó d'olówó oh-oh
Ẹdá mí jọọ (orí mí jọọ oh)
Alola fari gi noti, seri moda fa'yallahu (fa'yallahu)
Bàbá dá mí lóhùn (dá mí lóhùn)
Àgbà dé eee (àgbà dée)
Àgbà dé k'ọn tó gb'ohùn Rolling Dollar
(Yeah, ayy-ayy-ayy)
(Bàbá dá mí lóhùn)
Fali uli faki ilaina (ẹlẹda má sún)
(Yeah, who's here?)
Lyrics powered by www.musixmatch.com