Lyrics

Ojojumọ ni tole
Ọjọ kan f'onile
Ojojumọ ni tole
Ọjọ kan f'onile
Bo wù ẹ' ko ṣe kìràkìrà
Bo wù ẹ' ko ṣe kàtàkàtà
Kìràkìrà orin ayé o
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' Mr. Diva
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' Mr. Diva
Kí là ń jẹ tá ò jẹ rí o
Kí là ń mu tá ò mu rí o
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' pẹ'lẹ'
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' pẹ'lẹ'
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ'
É wọlé
Ó wọlé
Eeeeee ...
Ó wọlé
É wọlé
É wọlé
Ojojumọ ni tole
Ọjọ kan f'onile
Bo wù ẹ' ko ṣe kìràkìrà
Bo wù ẹ' ko ṣe kàtàkàtà
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' Mr. Diva
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' pẹ'lẹ'pẹ'lẹ'
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' pẹ'lẹ'pẹ'lẹ'
Pẹ'lẹ'pẹ'lẹ' pẹ'lẹ'pẹ'lẹ'
Ó wọlé
Ó wọlé
É wọlé
Written by: Kaleta
instagramSharePathic_arrow_out