Music Video

KING SUNNY ADE-E BA MI DUPE F'OLUWA (LET THEM SAY ALBUM)
Watch KING SUNNY ADE-E BA MI DUPE F'OLUWA (LET THEM SAY ALBUM) on YouTube

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
King Sunny Ade
King Sunny Ade
Performer
COMPOSITION & LYRICS
King Sunny Ade
King Sunny Ade
Songwriter

Lyrics

[Verse 1]
Mo de o Baba, mo wa ṣọpẹ, ore nla
Baba ti gba awọn ọmọ rẹ lo tu mi ninu
Ẹ ba mi dupẹ f'Oluwa to ran mi lọwọ
Baba gba mi lọwọ ìṣòro ka to ni jẹ
Emi o fi fún Oluwa fún oore rẹ
Ọpẹ mi pẹlu ẹsin mi o tu mi ninu
[Chorus]
Mo ti dá majẹmu o e, mo n san majẹmu mi o a
Fun Baba oloore ọfẹ
To ṣeleri, to muṣẹ a
[Verse 2]
Mo de o Baba, mo wa ṣọpẹ, ore nla
Baba ti gba awọn ọmọ rẹ lo tu mi ninu
Ẹ ba mi dupẹ f'Oluwa to ran mi lọwọ
Baba gba mi lọwọ ìṣòro ka to ni jẹ
Kini n o fi fún Oluwa fún oore rẹ
Ọpẹ mi pẹlu ẹsin mi o tu mi ninu
[Chorus]
Tori mo ti dá majẹmu o e, mo n san majẹmu mi o a
Fun Baba oloore ọfẹ
To ṣeleri, to muṣẹ a
[Verse 3]
Ore ọfẹ lo damisi, mo mọ iyẹn na
Mo dọlọlá loju ọta mi, emi a jo
Iku fo lọ, arun ṣegbe o, eyi tọpẹ
Baba wa leti ọdọ mi to n wo mi lọwọ
Ẹ ba mi jo ẹyin ara mi
Ile-ayé, k'ọpẹ mi, ogbo atọ la n tọrọ
[Chorus]
Mo ti dá majẹmu o e, mo n san majẹmu mi o a
Fun Baba oloore ọfẹ
To ṣeleri, to muṣẹ a
Written by: King Sunny Ade
instagramSharePathic_arrow_out