Featured In

Lyrics

Ma jaiye oni o
Mi o m'eyin ola o
Ma jaiye oni o
Mi o m'eyin ola o
Ma jaiye oni o
Mi o m'eyin ola o
Ma jaiye oni o
Mi o m'eyin ola o
Iba akoda to da ti e s'ori ewe
Iba akoda to da ti e s'ori ewe
Iba aseda to da ti e s'ile ipepe
Iba aseda to da ti e s'ile ipepe
Iba atete ko d'aye to da ti e s'ofurufu
Iba atete ko d'aye to da ti e s'ofurufu
Mo se iba araye e je ki n j'aye ori mi
Ma jaiye oni o
Mi o m'eyin ola o
Ma jaiye oni o
Mi o m'eyin ola o
Written by: King Sunny Ade
instagramSharePathic_arrow_out