Top Songs By SPINALL
Credits
PERFORMING ARTISTS
SPINALL
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Oluseye Sodamola
Songwriter
Olamide Adedeji
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
SPINALL
Producer
B Banks
Producer
Lyrics
(Hello so get ready for take-off)
(We are about to get high up in this bench)
(Ebengs Toby oh)
You know what time it is
They call me DJ Spinall
King Baddo
The Cap
Shorty asking me for mula
There is nothing I can do, oh
Go and meet your boo naa
Ọkọ ìyàwó elo blue
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
Rasheeda oh?
(Present)
Tinuke oh?
(Present)
Modina oh?
(Present)
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
Chidinma oh?
(Present)
Ngozi oh?
(Present)
Nneka oh?
(Present)
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
Áro, ọ̀n wárún
O dí stingy, jọwọ náwùn
Ọ fẹ fí caterpillar rẹ̀ kọlú kẹkẹ mi
P'ẹlú égun Igbo anyanwun
Break light mi oṣísẹ̀
Mo tí signal rẹ tẹlẹ naa áb'ọpọ ọrọwọ́ mí?
DJ Spinall mo gbé sinú motor kàlẹ yí
Òn kí ò, àb'ọpọ ọ gbọràn ni?
LV tọ wá lárà mí design ni
Oun láwọn oyinbo n pè ni Louis Vuitton
Á ṣe t'eko dé ni
Kíní búrúkú oyinbo n bẹ lẹnu wà bí t'ítọ
Uncle, excuse, sir
Are you her boyfriends?
You smoke fish, your eyes red
You fight lion with tribal mark
Am sorry
Shorty asking me for mula
There is nothing I can do, oh
Go and meet your boo naa
Ọkọ ìyàwó elo blue
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
Rasheeda oh?
(Present)
Tinuke oh?
(Present)
Modina oh?
(Present)
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
Chidinma oh?
(Present)
Ngozi oh?
(Present)
Nneka oh?
(Present)
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
Ha, wo bàdí áràn rẹ
Front to back ọwọ rẹ
Oh my God, Jesu
Look at that butt!
Sule
Ìbàdí rẹ, bábánbá re
Ṣẹ pé mejí ko lé dí binary
Àwọn eleyí bangalee
Ẹja ọsàn yí, àmá dín finally
Mu-mu-musulumi ní ọ ní, tábí mále?
Fí mí ṣọkọ àbí ọ fí mí ṣalé
Dákún jọ̀ jẹ n bá nbẹ
Tí m ba bámbẹ tàn, ma tún wá gbé ẹ lọ ṣ'áyé n mále
Yetunde Madonna
Ká lọ waterside
Kìn fún ẹ l'Arizona
O mà understand
Yeeba
Shorty asking me for mula
There is nothing I can do, oh
Go and meet your boo naa
Ọkọ ìyàwó elo blue
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
Rasheeda oh?
(Present)
Tinuke oh?
(Present)
Modina oh?
(Present)
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
Chidinma oh?
(Present)
Ngozi oh?
(Present)
Nneka oh?
(Present)
Àwọn ọmọ ẹlẹ yà pákoro
Tàn màn fún mí n'kínì tán wí yí
They call me the unstoppable DJ Spinall
A.k.a., a.k.a. The Cap
Baddo
Skippo baba
Ebengs on the beat
Ìyànu a ṣẹlẹ
Written by: Olamide Adedeji, Oluseye Sodamola