Paroles

Karanjagbon awo inu Igbo Ijokun worowo awo odan Mawo mawo awo ojola Adiafun erigi alo ti o jagbon obi Kerigi alo o to jagbon obi tan Ifa ni ire gbogbo a maa wole toni Ire gbogbo wole tomiwa Ire gbogbo Ewi falara eni o fenuyo wi temi Eso fajero eni o fenuyo wi temi Bire ba nbe ni waju ori mi mama sayi gbemi debe Ire ire ire Ewi falara, eso fajero Enuyo, enuyo Nitoripe áraye buru, eniyan soro oooo Awon lan ni nwa buyo, wo nke gbanjare gbanjare Aye lo ni nwa bumi, aye nke gbanjareeeee Ewi falara, eso fajero Enuyo, enuyo Awon lan safeeri fayan Won tun sarinako fadiye mi Enu araye kangba, eru araye nbami oo Enuyo, enuyo Ewi falara eni o fenuyo wi temi Eso fajero eni o fenuyo wi temi Bire ba nbe ni waju ori mi mama sayi gbemi debe Ire ire ire Ewi falara, eso fajero Enuyo, enuyo Mo fenu pere si iseda mi N o kumo oo, n o kumo oo Emi ti foju bodu Mo rire Mo fire dade, Mo fire dadeee Mo foju bodu Ire ire ire nitemi Ori ti nsunkun ati dade ti dade Orin mi tiwo ejigbara ileke Enuyo, enuyo Ewi falara eni o fenuyo wi temi Eso fajero eni o fenuyo wi temi Bire ba nbe ni waju ori mi mama sayi gbemi debe Ire ire ire Ewi falara eso fajero Enuyo, enuyo Ori mi mama buru Iseda mi mama gbabode Fenuyo, fenuyo wi temi Kori, Ori o ba mama gba O ba mama gba ooo O ba mama gba ooo Ori o ba mama gba ooo
Writer(s): Teledalase Ayomide Ogundipe Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out