Lyrics
Hey Jago, hey Jago
Hey Jago, hey Jago
You dey press money before (that's right)
That one na old taker (okay)
Me self go press for sure (you be what?)
I be the new taker, ah-ah (Shoday, ki lo de?)
Wọn ti gbezome (jẹ ọ mọ)
Old taker ti gbezome (wahala)
Ma lọ bezo mi
Ọmọ aunty mi no gbezome (fun wọn)
Hey Jago
What's popping, Jago? (Biggest)
High fashion Jago
Figo o ma ki n ṣe wazo o-o (they know)
Hey Jago (Jago)
Emi leeyan Jago (one on one)
Shoday eeyan Paso
Lambo o ma ki n ṣe wazo o-o
Hey Jago (number one)
Gbogbo aṣọ lo ni bata
CEO High Fashion ti a
Ọmọ Tiamiyu gan-an, gan-an (jẹ ọ mọ)
Wọn da mọ l'Oke-Koto
Atobajẹ wọ Morikaz
Oju-Irin, Pencinema
Aja one, aja two, gbe wọn sare wọ Switzerland
Wọn damọ l'America
High Fashion wọ Canada
O yeruku, Jago is loud
Ti n bari 50 dollar, maa ganu sibẹ
No money is ever enough (at all)
Ta, ta, ta bi Dangote
Kowo mi kun soke
I left home to feed home
Mo ja de tan, wọn se jollof
Go hard or go home
Ọmọ iyami, mo sa lọ'le, ay
Hey Jago (hey Ja')
What's popping, Jago? (I don't know)
High fashion Jago
Figo o ma ki n ṣe wazo o-o (number one)
Hey Jago (zero, kowo pọ)
Emi leeyan Jago
Shoday eeyan Paso
Lambo o ma ki n ṣe wazo o-o
Hey Jago
Gbogbo aṣọ lo ni bata
CEO High Fashion ti a
Ọmọ Tiamiyu gan-an, gan-an
Wọn da mọ l'Oke-Koto
Atobajẹ wọ Morikaz
Wọ High Fashion, wọ Canada
O yeruku, Jago is loud
Hey, Jago
Jago, Jago, Jago
Ọmọ lile lapa Agege, wọn damọ (Yo X)
Yebo
Gi, gi
Writer(s): Poco Lee, Rahman Jago, Shoday
Lyrics powered by www.musixmatch.com