Lyrics

T reign on the mix Lal-amru amri wala taqdiru teqdiiri Walal umuru lati tejri bi taqdiiri Bii khaalikun, roziqun man sha-a yaf-alu bii Ahato bi ilimuhu min qobuli taqdiiri Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Keda to waye, ma l'olohun ti seto Ninu oyun eda igba tonbe logoji ojo Lotiran malaika kan, kon gbe kadara e s'orun fun Yio pe biò nipe, yio pe biò nipe Yio la ni biò nila gan o, kadara kowa, ilahi oba mi tiko Teda ba ndogbon, olohun loni final say Kadara tigbe, olohun lonwo akoko eda Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Ba-adal istiadza wal-basmala Wataquu fitnatan la tuhzibana ladzina zolamu minkun khaasotan Wa-alamu anna llaha shadidul iqobi Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Seri teda ba nkanju to s'ogun owo gan te o mope Ola tako mo, lo nfikanju fa kole po o Ola ojo ola re, ola ojo ola re Gbogbo e naa lonfapo o, tio ba sora Tiò ba sora, yio jiya yio situn kan omo gan Nitoriwipe yio degun leyin toba ku tan Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Ninu oun gbogbo, eyi t'olohun oba da Ose wa jeti Eda adamo lo yato o, kotokoto aye ni Gbogbo nti owo o to o Mafi gòngò fa, lomo adamo yio ma wi Toba wa jasiparun, omo eda a ma gekaje ni Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Seri kaje kalemu Seri kaje kalemu, ti eda nfojojumo wa Ounje oòjo, sebolohun lomase Ajoke aye ni, be gbagbo be o ba gbagbo Tebi banpani lat'owuro koto dale Oba to d'enu nibūmbu ase oun toma je Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Eba maje ka kanju kagba f'olohun aseda o Ona atije, mio sope a ma ma wao Igbiyanju ni, mio sope a ma mase o Sungbon oun tio lodi, oun tio lodi Si t'olohun ni o da, eyi tio tako ilana annabi nio to o Nibi tatise, k'olohun o forijiwa Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Haa seri katepa mose, kasi f'adua naa kun Katun ma toro gbogbo nto wiwa tafe Oun yiowu ka toro, ashiri bibo sha lagba o Komaseni to nlani, koseni to nlani Koseni to nlani, ayafi olohun mi nikan Mase gbekele elomi, ilahi shani ko gbojule Kadara tigbe, olohun lo l,agbega eda o mo, se leda nsareka Onsare atila, olohun nwo akoko fun Olohun nwo akoko fun, olohun nwo akoko fun Olohun nwo akoko fun, olohun nwo akoko fun Allahu allah, yah hayyu, yah qoyyumu Allahu allah, yah hayyu yah qoyyumu Allahu allah, yah hayyu, yah qoyyumu Allahu allah, yah hayyu yah Qoyyumu Iwo naa ni, lole seun nti eda nwa o Iwo naa ni, lole seun nti eda nwa o Eni gbekele elomiran leyin re Ijakule ma lonitoun nbere Emi o nifi olohun sile siun toda Allahu allah, yah hayyu, yah qoyyumu Allahu allah, yah hayyu yah Qoyyumu Isilamu yi o oo, isilamu yi mio ni fisile laise o Tori pongbemi o, tori po ngbemio, koma damimole ri, tikinikan base Mogba wipe idanwo ni, binpari idanwo Binpari idanwo igbadun ni falala faalala Allahu allah, yah hayyu, yah qoyyumu Allahu allah, yah hayyu yah Qoyyumu Kalimo kan nbe toba wa ninu aye eda o, abeegbo Gbolohun kan nbe, toba wa ninu aye eda Aye eda adun bi oyin wallahi tallahi Kalimo yen, la ilaha illa llahu nio Allahu allah, yah hayyu, yah qoyyumu Allahu allah, yah hayyu yah Qoyyumu Toba k'owokan adan afi rogi Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye T'eyan ba wa sodo e tonbere ore Ranwon lowo Allahu sha nio sesan oore Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye T'eyan ba wa sodo e tonbere ore Ranwon lowo Allahu sha nio sesan oore Oba to dagi ope tun dasofun, ope tun wora e ola tun yika L'ope ba fara e saraye loore Nigi ope fiwan niyi loju omo araye Toba k'owokan adan afi rogi Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye Teyan bawa sodo e tonbere ore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Sebolowo sha niwo bose lowoto, owo towa nipamo sole natan Atomo atomo omo se ele jo natan, tiwon bawa sodo e tonbere ore Ootie niso pooni wabere oro Owe sonbi sorin meja loma npa, oro tio ba'kungbe loma tun jabo Lonso sawon alaini tonbere ore Igi ope tunwa sanfani ju iwo lo Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye Teyan bawa sodo e tonbere ore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Sebolola sha niwo bose lola to, gbogbo dukia aye shaloni pata Tokunrin bawa sodo e tonbere ore, wa so funwon pooni bose lolato Oro pon o wulo fun e lomanso Sungbon toba j'obinrin lotoe wa Wa s'owo di mario nibi loma daku si Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye Teyan bawa sodo e tonbere ore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Iwo tojeoe erū lofi k'olajo, lonibara basi tewo o sope what? Pe"oro lapa lese kini o lo wase fun? Botun reni tio dape wa tun riwi Olel'oju won o fo pe se non ndogbon Ese towa lorun e acre kan ni Boomo tele se ore o je lo tūba Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye Teyan bawa sodo e tonbere ore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Innama sodaqotu lil-fuqorai Wal-masakini wal-amiliina alayha Wal-muwallafati qulubuhum Wafi riqobi wal-garimina Wafi sebili llahi wabni sebili Faridotan mina llahi, wallahu aleemun akimun atore Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye Teyan bawa sodo e tonbere ore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Alfuqorau t'olohun minso, al-masakinu t'olohun minwi Kiise pawon ton o pe lonsoro won Bonpe lara bon ò pe tore lonwi Boosi lowo lapo tio lefi tore Kosoro sadaka gan to loro enu Soro tutu tosida tole moriwu Mawo towo tiosi toofi tore Kan sadua falaini kogba laada Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye Teyan bawa sodo e tonbere ore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Olowolayemo tiyin nmotun riri Eyin o tore nibi teyan o si afi kojupe Kojupe kero tunpo konle kan saara O sodiun tongba award fun soye koribee Ore karimi sha niyen tio ni lada Tiwon bawa sodo e tonbere ore Bo won lashiri koma tuwon saye Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye Teyan bawa sodo e tonbere ore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Haa, iwo iyawo oloro to m'aye le tunko Aya shekere olowo ilu tawon aye nwi Iwo nboko e ja pe kiwon to nawo Po gbodo ma sinibe kotole tore Boya o jebi bio basi jebi wani no o Toko e batun gbiyanju kole tore gan Waso wiponpoju poti bawon je Abi ko kosi lokan pe kole kere Abi kotun magba pe kole tore gan Teyan bawa boko e tonbere ore Lo'pore fawon alaini mabolaje Toba k'owokan adan afi rogi Eni tokuniku sha lanba jaye Teyan bawa sodo e tonbere ore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Dunwon ninu allahu sha nio sesan fun e Ranwon lowo allahu sha nio sesan oore Atiya o ooo, ati fun Atiya o, ati fun Eni aba ya onifokanbale gbese nio Eni afun a dabi eni jifa adupe Atiya o, ati fun Atiya o, ati fun Eni aba ya onifokanbale gbese nio Eni afun a dabi eni jifa adupe Ewo, seri gbese ni yiya O loju eniyan tonroju lati sanpada toba ya Ayamasan eda eyan o, toba legberun nile Koni san ogorun eyi toya, toba sebe tofiku Kogba wipe ohun loje Tawon ebi e o balesan Olohun ase esan fun ni, ha, ayiya Atiya o, ati fun Atiya o, ati fun Eni aba ya onifokanbale gbese nio Eni afun a dabi eni jifa adupe Ewo, ofin olohun ma lowipe Kaka keniyan o yawo O better kitoun toro Tio bareni tolefun, yawon tomo polesan, kodajo abigba tomope Yio rorun latisan, towo tóòrokan bawa de Ore malo gbeshiro le, ranti owo eyi toya Esu tio sinbe tofiya Aduro pe komale san Iwo mawobe koya san Kole rimiran tun riya atiya o Atiya o, ati fun Atiya o, ati fun Eni aba ya onifokanbale gbese nio Eni afun a dabi eni jifa adupe Olohun ma mafisewa aare tio gboogun Todipe awa nyawo Bukata tao nile gbo, mako siwa nigba mo O dokun lomi tiogbe, o dosa lomi tio tan Owase makkah nibiti lododun tawon aye npeju Awon tirue selesi, yigba pada olola Eru re ma nbe e o Shola tio niparun funwa kamale dupe tan oriyomi atiya o Atiya o, ati fun Atiya o, ati fun Eni aba ya onifokanbale gbese nio Eni afun a dabi eni jifa adupe Baba olowo ele erora Bee iya, olowo ele erora Contractor tio gbase ri Contract kan malo yoju, nipajawiri lotunje Kise naa malebo loje ko sato e wale Oun tode mawi, onsope tere badetan, fifty fifty lemapin, toun balo koreyan ya Loba pada warie Owe toopa matun nipe B'abebe roke nigba igba ibi pelebe ma naa ni Yio filele o daju, igba tio nibi anlomo Loba yagba boseso Olohun ni oun o fe Edekun owo ele nyiya atiya oriyomi o Atiya o, ati fun Atiya o, ati fun Eni aba ya onifokanbale gbese nio Eni afun a dabi eni jifa adupe Olowo oloro atolola, tan o ronu pawon a yawo Adanwo tan o ronusi, lowole towon logan Nonba deni tonyawo, won f'owo oun sise Atoju owo pelu ere o, ole ba jagba ojilo Awon tirue selesi Allahu wa sanu funwon Shiju aanu wo won kia Eru re ma unbebe o Dagba pada kon rina ha atiya o Atiya o, ati fun Atiya o, ati fun Eni aba ya onifokanbale gbese nio Eni afun a dabi eni jifa adupe Bee Olohun o gbagbe ati soooo-re Olohun o gbagbe ati soore Afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Olohun o gbagbe ati soore, afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Olohun o gbagbe ati sooo oore Olohun o gbagbe ati soore Afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Olohun o gbagbe ati soore, afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Jendupe nigbeyiiiiiiin o Jendupe nigbeyin, kawon eyan wabami dupe Allah, jendupe nigbeyin Kawon eyan wa bamidupe Olohun o gbagbe ati soore Afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Olohun o gbagbe ati soore Afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Iya o lowo baba o ni, won ferawon won biwa sayeeeee Iya o lowo baba o ni won ferawon won biwa saye Nireti p'aye ti eshin orije iru lomaje Mamase doju tiwon wola igba tere won doyun Atife ton ni sirawon, iwo lole bawonse Jondupe nigbeyin, kawon eyan wabawon dupe Maso posetan atise tiwon, ma wowon niran Ma fawon otawon loroso Olohun o gbagbe ati soore Afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Won nise logun ise laye o, sha lopo eyan fin tepamo Eyan tosise bi erin toje ije eliri nikawi Eni tojoko gbowo wa nposise ni ole Sungbon taba ranti owe Kasise bi eru, ko kuku da nkankan Olohun lo ngbeniga Allahu joo wasanu won Sisesise laye konjere kon kore dele, maso posetan atise tiwon, ma wowon niran Ma fawon otawon loroso Olohun o gbagbe ati soore Afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Olohun gbenumi sase ooooo Olohun gbenumi sase fawon eyan tojomo nonwa Konma sowon loruko eyi ton o sowon njo sunna Won a pewon ni agan soruko eyi bojumu ni Olohun tosewa mamasai wa rowon laso Olohun to sagbe mamasai bawon ponmisi Iwo logbe ile omo dakun ilahi wa fomo si Wola robbana, atina fi duniya hassnatan wafil- Akhirati hassanatan Waqinna adzaba naar Je ondupe nigbeyiiiin, Allah Je ondupe nigbeyin kawon eyan wabawon dupe Ma so posetan ati setiwon, mawo won niran Ma f'awon otawon loro so Olohun o gbagbe ati soore Afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Olohun iwo ma legbekele toriwo lole bawase Kaka ka besu lowe ola kaya d'opo olohun mutan Eni raja ateni reshin, talo jere ju ki ewawi? Eni gba ibeere mi toso idi toba fi j'aja Eyan toba mu eshin koso idi roba fi jeshin Toba gba ibeere miiiiii o Wa dupe nigbeyin Awon eyan a ba e dupe, ma malo setan atise tiwa Mawowa niran Ma fawon otawa loroso Olohun o gbagbe ati soore Afi tio baya, maso posetan atise temi Mawomi niran o, ma fawon otami loroso Allah, segan mi dogo oo Segan mi dogo Kepe ayemi dire Mase dojutimi Allah ire ni monwa Segan mi dogo Kepe ayemi dire Mase dojutimi Allah ire ni monwa Annabi ibrahima o, ko ko kahaba tio Annabi sulaimana, ko wola olohun ti Yusufu owa isho olohun tio Segan mi dogo Kepe ayemi dire Mase dojutimi Allah ire ni monwa Annabi ayuba o, kowa alafia ti Annabi musa kalamu llah, ko gbohun olohun ti Annabi issa ruhu-llah, kojise olohun ti Ma majen ware ayemi ti o Segan mi dogo Kepe ayemi dire Mase dojutimi Allah ire ni monwa Muhammadu rosulu llah Muhammadu habiiba llah Omo amina, muhamma omo abudallah Kojise Olohun ti bee, kowa ike Olohun tio Segan mi dogo Kepe ayemi dire Mase dojutimi Allah ire ni monwa Sebi eyan shani mko moshudi omo abiola Kowola olohun ti, eyan sha l'eleganza o Okoya rasaki, kowola olohun ti Eyan shani folawiyo, ko wola olohun ti Bee kotun sinlohun ti, ma majen ware ayemi ti o Segan mi dogo Kepe ayemi dire Mase dojutimi Allah ire ni monwa Sebeyan shani abidini, ege oba l'oando Eyan tun ni wasiu, tantala onipo ola Eyan shani saidi, yaro oba ni mobil Won o wola olohun ti, ma maje nwola ayemi tio Segan mi dogo Kepe ayemi dire Mase dojutimi Allah ire ni monwa Eyan sheu ismaila, aderemi t.k Khalifah abu subuanna llah Wali hamdulillah, alfaa mini Ko wola olohun ti bee kotun sinlohun tio Segan mi dogo Kepe ayemi dire Mase dojutimi Allah ire ni monwa Ma mase doju timi allah ireni monwa Mase dojutimi Allah ire ni monwa Ma mase dojutimi Allah owo ni monwa Mase dojutimi Allah ire ni monwa Ma mase doju timi Allah ola ni monwa Mase dojutimi Allah ire ni monwa
Writer(s): Oriyomi Sanni Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out