Top Songs By Florocka
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Florocka
Performer
Akinwunmi Oluniyi Akiremi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Akinwunmi Oluniyi Akiremi
Songwriter
Lyrics
Rah rah rah
Rah rah rah rah
Elu agogo
Elu agogo
Elu agogo
Kèrèsimési
Elu agogo
Elu agogo
Olugbala wa dé o
Elu agogo
Elu agogo
Elu agogo
Elu agogo
Kèrèsimési o
Elu agogo
Elu agogo
Olugbala wa dé o
Elu agogo
Awon olusó agutan
Won só ago won
Imole yi won kà
Won ni kilode o
Asé Olugbala la bí
(Olugbala wa káàbó)
Awon olusó agutan
Won só ago won
Imole yi won kà
Won ni kilode o
Asé Olugbala la bí
(Olugbala wa káàbó)
(Ehh yeah yeah, yeah yeah, yeah yeah)
(Elu agogo)
Elu agogo
Elu agogo
Elu agogo
Kèrèsimési
Elu agogo
Elu agogo
Olugbala wa dé o
Elu agogo
(E bami lu agogo)
Elu agogo (Agogo ayo)
Elu agogo
Elu agogo (Agogo eda, say yeah)
Kèrèsimési o
Elu agogo
Elu agogo
Olugbala wa dé o
Elu agogo
Irawo kan iyan loju orun
Si awon omo yen meta
Awon angeli ko orin loke o
Pe Olugbala ti de
Olugbala wa káàbó (Olugbala wa káàbó)
(We welcome you Lord, yeah...)
E fi ope fun Baba (Baba)
E fi ope fun Omo (Omo)
E fi ope fun Emi mimo fun Baba Ara aiye
Olugbala wa káàbó (Olugbala wa káàbó)
(We welcome you Lord, yeah...)
(Elu agogo)
Elu agogo (Yeah eh yeah)
Elu agogo
Elu agogo
Kèrèsimési (Go tell it on the mountains)
Elu agogo
Elu agogo (Over the hills and everywhere)
Olugbala wa dé o
Elu agogo
(E bami lu agogo)
Elu agogo (Agogo ayo)
Elu agogo
Elu agogo
Kèrèsimési o (Go and tell it everywhere)
Elu agogo(Tell somebody)
Elu agogo
Olugbala wa dé o
Elu agogo
(Away)
O de
O de o
Obanla de o, wura de
(E wi)
O de
O de o
Obanla de o, wura de
O de
O de o
Oba eri ma de, o ma ti de
O de (E je ko wole wa)
O de o
Obanla de o, wura de
O de
O de o
Obanla de o, wura de
O de (E si ilekun o)
O de o (E je ko wole wa)
Obanla de o, wura de
E gbe ori yin soke
Eyin e nona anikajumo
Gbe yin soke
Eyin ekun aiyeraye
O de
O de o h
Obanla de o, wura de
He comes
See him coming
I can see the King of Glory coming
O de (The gates of hell)
O de o (shall not prevail)
Obanla de o, wura de
Said I can see
The Glory of the Lord
Coming upon me
O de
O de o
Obanla de o, wura de
Oh oh oh yeah...
Writer(s): Akinwunmi Akiremi
Lyrics powered by www.musixmatch.com