Music Video

Featured In

Credits

COMPOSITION & LYRICS
Tope Alabi
Tope Alabi
Songwriter

Lyrics

Olorun, iwo latobi ju
Iwo ni gbogbo aye pe ni Baba
Angeli wole fun lorun
Ise owo re yin o
Oba nla, Olorun nla ni
Adahun ro
Gbogbo aye wari fun o baba
Adahun so
Iwo lo wo di Jericho
Iwo ladahun se
Iwo lo ko Jerusalem
Gigbe ga ni o oh
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Oba nla ni o oh
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Tito bi re gaju aye lo
Ko seni ta le fi o we Baba
Fiyin f'Olorun ni bi giga oh
Iwo to ba mo riri re
Boti tobi to, ko se f'enu so
O joko lori obiri aye
Ise nla ni ise re atobiju
Eni nla ni o, ka yin pupo pupo
Gbega, gbega, eniyan gbega, gbega
E fiyin fun gbogbo, angeli re
E fiyin fun gbogbo, eyin omo ogun re
Orun, osupa, e fiyin f'Oluwa
E yin Oluwa lati aye wa
Eyin erimi, ati dede ikun omi
Gbega, gbega, eniyan gbega
Baba
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Gbega

Oba nla ni o, Eleruniyi
Gbigega ni o, Oba to mo iye irawo oh
Iwo la o ma yin ye, titi lailai
Titobi re o, ko lakawe oh
Ope, iyin fun Baba nla Baba wa
Fun oun nikan tin sise iyanu
Angeli yi ite re ka titi lailai
Ope, iyin, ola fun Olodumare
Akoda aye, aseda orun
Olorun ni o, onki se eniyan rara
Omimi tin m'ile, aye yi, iwo nikan l'Oba
Oba ni oh
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Gbega, eranoko igbo, eja inu ibu, eye oju orun, orun awon orun eh
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Emi tin be loke orun, Oba aye ati omoalade, e fiyin fun nidi mimo re

O tobi oh, o ga, Olorun gbangba, gbangba

Oba nla ni
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Gbega oh, eranoko igbo, eja inu ibu, eye oju orun, orun awon orun eh
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Emi tin be loke orun, Oba aye ati omoalade, e fiyin fun nidi mimo re
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
O tobi oh, o ga, Olorun gbangba, gbangba
Olorun gbangba, Olorun fenfe, Olorun gborogodo, Olorun ribiti, Olorun kanjokanjo
Gbega oh

Written by: Tope Alabi
instagramSharePathic_arrow_out