Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Mike Abdul
Mike Abdul
Performer
Ayodele Fashe
Ayodele Fashe
Keyboards
Joshua Fashina
Joshua Fashina
Bass Guitar
Segun Shaba
Segun Shaba
Drums
Famoriyo Richard
Famoriyo Richard
Guitar
Peter Ilelabayo
Peter Ilelabayo
Percussion
Emmanuel Abiodun
Emmanuel Abiodun
Percussion
Temitope Oguntola
Temitope Oguntola
Background Vocals
Olushola Fabiyi
Olushola Fabiyi
Background Vocals
Tosin Muhammed
Tosin Muhammed
Background Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Hessking
Hessking
Songwriter
Michael Olayinka Abdul
Michael Olayinka Abdul
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Olaitan Dada
Olaitan Dada
Mixing Engineer

Lyrics

Eyin omo jesu owo yin da
Eje ka rowo yin o
Owo yin ma la fe ri
Oruko Jesu dun bi oyin
Teba ngbo who goes you
Emi ni emi ni emi omo emi ni
Emi ni ma beru oooooooo
Emi ni ma foya ooooooo
Chorus:
Identity ti Moni
Jesu ti mo gbe sori
Bi kokoro se je seni tofe wole
B’okini se je o si ranso ranso
Bi biro se je t’awon alakowe
B’elubo se je sawon alamala
Loruko jesu je si gbogbo onigbagbo
Toba dele olorun malo fara we enikan
Sentima dupe je kope yen ko po si
Sentima worship to rolorun lo logo
Sentima gbadura malo bawon sun para
Toba ti leti gbohun ti emi nso.
Chorus:
Identity ti Moni
Jesu ti mo gbe sori
Awon to duro o to duro
To duro doluwa won Afi ye fo bi idi o
Bon sare o non sare
Omo koni re won bi elemi meje ni
Obaye binu o ye binu
Ye binu omo jesu ofe bolorun dogba ni
Konipe mo konipemo
Manifestation ti mo wi oni pe mo o
Tawon omo jesu ire.
IRE
IRE
IRE
IRE
IRE
IRE
IRE
Written by: Hessking, Michael Olayinka Abdul
instagramSharePathic_arrow_out