Featured In
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Tim Lyre
Performer
Boj
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Timothy Oyesanya
Songwriter
Bolaji Odujakan
Songwriter
Kenechukwu Freeley
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
KC FREELEY
Producer
Lyrics
[Intro]
O ṣe
[PreChorus]
Duro na
Emi ti mi lock in
Wọn fẹ sọ pe mo lucky gan-an
I been putting the work in
Everything that I touch, ina, idan
O jin far far, o n lọ
O pọ, o n pawo lọ
Ọmọ to pọ, o n bọ
[Verse 1]
She was coming 'cause its going
And it must be the liquor controlling
All the movements, all the action
In my system right now
I can see, by your stance
Kokoro meji lo pade
I can play, she can dance
She been dey sing like Amaarae
[Chorus]
O n yi bọ, o n yi lọ
Oyinmọmọ on the double
O pọ yẹyẹ, yẹ
Olayiwọla
O n yi lọ, o n yi bọ, o n yi lọ
Oyinmọmọ on the double
O po yẹyẹ, yẹ
Olayiwọla
[Refrain]
O n yi lọ, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi, o n yi bọ
Oyinmọmọ on the double
Yeye yeah, o n yi lọ
[Verse 2]
Baby mi ṣo le jo?
Gbẹdu n lọ ṣo le jo?
You should already know
Ko le sohun to da to
Nigboro, nigboro
Ko ma la sohun to da to
Nigboro, nigboro
[PreChorus]
Duro na
Emi ti mi lock in
Wọn fẹ sọ pe mo lucky gan-an
I been putting the work in
Everything that I touch, ina, idan
O jin far far, o n lọ
O pọ, o n pawo lọ
Ọmọ to pọ, o n bọ
[Chorus]
O n yi bọ, o n yi lọ
Oyinmọmọ on the double
O pọ yẹyẹ, yẹ
Olayiwọla
O n yi lọ, o n yi bọ, o n yi lọ
Oyinmọmọ on the double
O po yẹyẹ, yẹ
Olayiwọla
[Refrain]
O n yi lọ, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi, o n yi bọ
O n yi lọ, o n yi, o n yi bọ
Oyinmọmọ on the double
Yeye yeah, o n yi lọ
Written by: Bolaji Odujakan, Kenechukwu Freeley, Timothy Oyesanya