Music Video

Wizkid - Ololufe (Audio) ft. Wande Coal
Watch Wizkid - Ololufe (Audio) ft. Wande Coal on YouTube

Featured In

Lyrics

I can't believe that she don't And the thing I believe go She say W mo cold O wa sọ pe W mi o cold o (P!) Wanna be on your show Wanna put me on your shoulder O ma fàṣẹ, she can play with the wall I dey fight you, gonna won with the wall Layẹmi, sọ fun wọn mo nifẹ, mo nifẹ ẹ gan ni Fine lady girl, you different, different gan ni o I no know why but mo miss ẹ, mo miss ẹ gan ni o Bad girl, I'm addicted, addicted gan ni o Iwọ l'ololufẹ, my darling Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ Iwọ l'ololufẹ, my darling Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!) (Hmm, sọ fun wọn mo n'ifẹ) (Mo ni, Fọlashade) (Sọ fun ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni o) Layẹmi, Ọlayẹmi, mo n'ifẹ Funkẹ, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ" Titilọla, hmm, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ" Mo ni, Fọlashade Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ife gan ni Iwọ l'ololufẹ, my darling Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ Iwọ l'ololufẹ, my darling Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ Ko, ko, ko, ko Konkobilo, ko-ko-ko Ọwá fẹ pàdé mí ní ìsàlẹ̀ Òye ká fún konkobilo Ko, ko, ko, ko Owa fẹ jẹ ko-ko-ko-ko Mo ni ko pàdé mí ní ìsàlẹ̀ Ìyẹn gan lo ṣe ko-ko Iwọ l'ololufẹ, my darling Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ Iwọ l'ololufẹ my darling Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!) Layẹmi, Ọlayẹmi, mo n'ifẹ Funkẹ, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ ẹ" Titilọla, hmm, so fun ẹ, "Mo n'ifẹ" Mo ni, Fọlashade Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni Gbé mi de bẹ Gbé mi de-, gbe- Gbé mi de bẹ, de bẹ Gbe- Wọn lo wa ji (gbé mi de bẹ) Wọn ní mo ji Wọn ní pe mo ji Ki ni mo de? Ani kí ló gbé? (Gbe mi) Wọn ni, "Ki lo wi? Mo ni mo de Wọn ni mi o dé Mo gbéra dídé (gbe mi) Mo gbéra dídé Mo gbéra dídé Mo gbéra dídé Mo gbéra dídé Mo gbéra dídé
Writer(s): Michael Collins, Wande Ojosipe Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out