Music Video

Reminisce - Orin feat. Olamide (Official Audio)
Watch Reminisce - Orin feat. Olamide (Official Audio) on YouTube

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Reminisce
Reminisce
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Remilekun Safaru
Remilekun Safaru
Songwriter
Olamide Adedeji
Olamide Adedeji
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Eskeez
Eskeez
Producer

Lyrics

[PreChorus]
How many woes?
How many foes?
How many struggle and fight?
How many sweat and tears, and blood I have to shed to be a man? Oh
E no easy I know
Dem want take me down low
Cause the wire never slowing down woah!
[Chorus]
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t'ọn n kọ? (Ẹ ṣe gan-an)
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t'ọn n kọ?
[Verse 1]
Ṣẹ ti gbọ orin t'ọn n kọ?
Isọkusọ t'ọn sọ
Gbogbo ikọkukọ t'ọn n kọ
Just bacause awa lọmọ t'ọn n sọ
[Verse 2]
Long time coming , but boys still running
Tap wọn ti gbẹ but ours still running
Ọta wọn ti wọn Topboys still gunning
Sperm wọn ti gbẹ ọmọ oro still cumming
[Verse 3]
Oju lasan lẹ ro pe wọn fi n di legende
Ẹ tẹ'pa mọ'ṣẹ ẹ fẹ di elpresidente
Ibo lẹ wa nigba ti mo n hustle ni Ebivande?
Dasaki, ko n tan lara ọmọ ọba men dey
[Verse 4]
Rule number 1, do more say less
Normally too much opata dey bring stress
Even when I don’t agree I’m gonna say yes
Baddo fayẹwo gbe hook yẹn wọle bi safe sex
[PreChorus]
How many woes?
How many foes?
How many struggle and fight?
How many sweat and tears, and blood I have to shed to be a man? Oh
E no easy I know
Dem want take me down low
Cause the wire never slowing down woah!
[Chorus]
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t'ọn n kọ? (Ẹ ṣe gan-an)
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t'ọn n kọ?
[Verse 5]
10 years in the trenches
12 years on top lai ṣe menses
Can't do nothing right, wọn ṣi ma fo
Bi ọṣẹ detergent, wọn ṣi ma ho
[Verse 6]
Reputation stainless
Been through tough times so I know what pain is
Seen a lotta sunshine so I know why rain is
Seen a lotta good days so I know what day it is
[Verse 7]
Nothing's gonna stop me o digba ti n ba jabọ
In about 6/7 decades mo ni igbagbọ
Ma kanra kanra everyday like it's my last
Marathon lere fuji yii mi o dẹ le gas
[Verse 8]
Examination ni mo dẹ ti pass
Ọja D baba eeyan best in class
GOAT conversations? Kiss my ass
Fuck all you rap ****, kalaz
[PreChorus]
How many woes?
How many foes?
How many struggle and fight?
How many sweat and tears, and blood I have to shed to be a man? Oh
E no easy I know
Dem want take me down low
Cause the wire never slowing down woah!
[Chorus]
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t'ọn n kọ? (Ṣẹ ti gbọ orin t'ọn n kọ?)
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t'ọn n kọ?
Written by: Olamide Adedeji, Remilekun Safaru, Segun Gabriel
instagramSharePathic_arrow_out