Top Songs By Tope Alabi
Credits
PERFORMING ARTISTS
Tope Alabi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Patricia Temitope Alabi
Songwriter
Lyrics
Olorun ara s'aye mi ni re, fimi dara to da Baba oo
Olorun ara, Oni'nu ara, fimi dara to wunmi o
Olorun ara s'aye mi logo, fimi dara to da Baba oo
Olorun ara, Oni'nu ara, fimi dara to wunmi o
Oba to mo mi, to ni mi, to da mi
Alara oni sababi wa s'aye mi nire
Mo fowo mi gba'rimi mu o, wa sanu ori mi
Mo fowo mi gba'rimi mu, wa sanu aye mi
Olorun ara s'aye mi ni re, fimi dara to da Baba oo
Olorun ara, Oni'nu ara, fimi dara to wunmi o
Olorun ara s'aye mi logo, fimi dara to da Baba oo
Olorun ara, Oni'nu ara, fimi dara to wunmi o
Iwo lo da da daa
To da ohun gbogbo saye
Odani to momi o, kima waye wa jiya
Edu'a Olohun gbogbo lowo, seke mi o Baba
Akan ii kere ainile lori
Aja ikere ee gbigbo
Ologbo ii kere a n leku paje o
Maje n kere si're owo re
Kin se rere laye, kima seru egbe mi o
Kima waye wa woran
Kint'egbe mi o, kin tun jogba lo
Waa 'bukun f'emi ooo
Olorun ara s'aye mi ni re, fimi dara to da Baba oo
Olorun ara, Oni'nu ara, fimi dara to wunmi o
Olorun ara s'aye mi logo, fimi dara to da Baba oo
Olorun ara, Oni'nu ara, fimi dara to wunmi o
Oba Alara, Oni'nu ara, babara ara n be lowo re
Eni to ku o ku lofi dara ti o to oo
Wafimi da repete ara nla, Awimayehun oo
Eleberu Ike, fimi dara to wunmi oo
Mikili ko o ku ofi dara ti o daa oo
Nebuchadnezari gberaga ofi dara ti o wun oo
Olorun ara s'aye mi ni re, fimi dara to da Baba oo
Olorun ara, Oni'nu ara, fimi dara to wunmi o
Olorun ara s'aye mi logo, fimi dara to da Baba oo
Olorun ara, Oni'nu ara, fimi dara to wunmi o
S'anu aye mi o Baba
Eni to ba fi dara ire
Kii fara sinu ku
Jekara ayemi kowu egbe mi o
Alara topo, Onike ara, fimi dara to wu aye mi
Apesin ola, Oba nla, Adagagede onilekun ore
Apela oloro to po
Onire jan ran abani mayo, wa fa ye mi dara ire
Olorun ara s'aye mi ni re, fimi dara to da Baba oo
Agbalagba oro, Oni bu Ola
Kiki da ara ni ofi da orun, ara nla to da aye
Opolopo oro
Ingbala Ola la, Aje ori oro
Ileke Ibikun
Oloopa ara
Olorun akoda ola
Ijinle oro to ga, ga, ga
Alara to po o
Ma fi mi da ara ti ko da
Baba alara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire
Written by: Patricia Temitope Alabi