Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Orlando Julius
Orlando Julius
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Orlando Julius
Orlando Julius
Songwriter

Lyrics

Well, ololufe
Dákùn, yé mà kọ mi, oh
Ti n ba n ṣè ẹ oh, olo mi pèmi ṣo fún mi
Ìwọ ni témi, titi dé ìnú ọkàn mi
Ṣè mi bi ẹ lògùn ọ̀rẹ́, ololúfẹ
Ìwọ ni témi, titi dé ìnú ọkàn mi
Ṣè mi bi ẹ lògùn ọ̀rẹ́, ololúfẹ
Èmi ni tírè, olo mi titi ayé
Ti n ba n ṣè ẹ oh, olo mi pèmi ṣo fún mi
Àdún m'ara dan, olo mi éyin fún jowó
Ṣè mi bi ẹ lògùn ọ̀rẹ́, ololúfẹ
Àdún m'ara dan, olo mi éyin fún jowó
Ṣè mi bi ẹ lògùn ọ̀rẹ́, ololúfẹ
Èmi ni tírè, olo mi titi ayé
Jẹ ká bẹ̀ Oluwa, ko fún wá lọmọ ye, well
Àdún m'ara dan, olo mi éyin fún jowó
Ṣè mi bi ẹ lògùn ọ̀rẹ́, ololúfẹ
Àdún m'ara dan, àdún m'ara dan, éyin fún jowó
Ṣè mi bi ẹ lògùn ọ̀rẹ́, ololúfẹ
Èmi ni tírè, olo mi titi ayé
Jẹ ká bẹ̀ Oluwa, ko fún wá lọmọ ye
Àdún m'ara dan, olo mi éyin fún jowó
Ṣè mi bi ẹ lògùn ọ̀rẹ́, ololúfẹ
Àdún m'ara dan, àdún m'ara dan, éyin fún jowó
Ṣè mi bi ẹ lògùn ọ̀rẹ́, darling témi
Written by: Orlando Julius
instagramSharePathic_arrow_out