Music Video

David G - Arugbo Ojo (Official Music Video)
Watch David G  - Arugbo Ojo (Official Music Video) on YouTube

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
David G
David G
Performer
COMPOSITION & LYRICS
David G
David G
Songwriter
David Gbenga Olusegun
David Gbenga Olusegun
Songwriter

Lyrics

Edumare Oba mi ni
Oba eh eh mh
Mo wole fun o Alagbada ina Baba mi o
Mo wole fun o ogbe nu mundia sododo
Mo wole fun o Atofarati bi oke won ni Baba
Mo wole fun o Arugbo Ojo
Mo wole fun o Baba awon tio ni baba
Mo wole fun o Kabio omasi o Baba mi
Mo wole fun o Ogbe nu mundia sododo ododo baba o
Mo wole fun o Arugbo Ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o Arugbo Ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o Arugbo Ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o Arugbo Ojo
Mo wole fun o Baba, mo wole fun o oh oh, mo wole fun o Arugbo Ojo
Kabiosi oh baba
Alagbada ina nio oo Baba
Arugbo Ojo nio ooo Baba
Baba awon ti ko ni baba
Emi mimo ma nio o Baba
Mimo mimo ma nio o Baba mi
Eru jeje nio Oluwa Oba
Arugbo Ojo o
Baba mi nio o Baba
Eleda mi nio Baba
Atorise nio o Baba mi
Ataye se nio oo Baba
Atowo se ma nio o Baba
Oloju ina nio o Baba mi
Emi mimo nio o Arugbo Ojo
Arugbo ojo nio o Baba
Kinihun eya Judah nio o Baba
Mo wole fun o Arugbo Ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o Arugbo Ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o Arugbo Ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o Arugbo ojo
Mo wole fun o, mo wole fun o, mo wole fun o Arugbo ojo
Mo wole fun o
Mo wole fun o
Written by: David G, David Gbenga Olusegun, Ebenezer Oluwafemi Iriem
instagramSharePathic_arrow_out