Music Video

Ilu le o | Dr. Victor Olaiya | Official Video
Watch Ilu le o | Dr. Victor Olaiya | Official Video on YouTube

Featured In

Lyrics

Ilu le o ko s'owo lode
Ilu le o ko s'owo lode
Obinrin n kigbe okunrin n kigbe kaluku lo n kegbe owo
Obinrin n kigbe okunrin n kigbe kaluku lo n kegbe owo
Abi beeko
Ani se e
Bi sisi mura gege won a ka e mole, ani
Bi sisi mura gege won a ka e mole
Mo beere e titi won o jise fun e ni, Ani se e
Iro lo n pa o owo lo n wa yen
Mo beere e titi won o jise fun e ni, anio
Iro lo n pa o naira lo n wa yen
Ilu le o ko s'owo lode
Ilu le o ko s'owo lode
Obinrin n kigbe okunrin n kigbe kaluku lo n kegbe owo
Obinrin n kigbe okunrin n kigbe kaluku lo n kegbe owo
Bi sisi mura gege won a ka e mole
Bi sisi mura gege won a ka e mole
Mo beere e titi won o jise fun e ni
Iro lo n pa o owo lo n wa yen
Mo beere e titi won o jise fun e ni
Iro lo n pa o naira lo n wa yen
Written by: Dr. Victor Olaiya
instagramSharePathic_arrow_out