Credits
PERFORMING ARTISTS
Sean Tizzle
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Oluwaseun Morihanfen
Songwriter
Lyrics
[Intro]
Blaq Jerzee on the beat
O ya
[Verse 1]
I want to dance however o, eh eh
Want to pop whatever o, eh
I want to groove however o, eh
O ya ti wọn bọọta o
[Verse 2]
Ah, emi at'wọn t'emi fẹ ṣaye nigboro
Me at'awọn t'emi fẹ jaye o
Emi at'wọn t'emi fẹ ṣaye nigboro
Me at'awọn t'emi fẹ jaye o
A ti gbe're wa de
Ah ko kan aye
As we enter the place ọmọ see gobe
[Chorus]
O ya k'ẹnikẹni ma na bọbọ yẹn
Ara wa ni o
Ara wa ni bọbọ yẹn
Ara wa ni
O ya k'ẹnikẹni ma wo baby yẹn o
Ọmọ wa ni
Ọmọ wa ni baby yẹn
Ehnehn
A mọ'ra wa o
A mọ'ra wa o
Ohh oh
Awọn t'awa mọ'ra wa o
A mọ'ra wa o
[Verse 3]
O ya ọmọ this year wey we enter o
Everybody ko prosper o
O ya mo maa r'owo tọju mama o
Because we go party till whenever o, oh yeah
[Verse 4]
Emi at'wọn t'emi fẹ ṣaye nigboro
Me at'awọn t'emi fẹ jaye o
Emi at'wọn t'emi fẹ ṣaye nigboro
Me at'awọn t'emi fẹ jaye o
[Chorus]
O ya baba anybody ko le mu ọmọ mi lọ (Mu ọmọ lọ o)
Tori ko ma proper o (Ko ma proper)
O ya k'ẹnikẹni ma na bọbọ yẹn
Ara wa ni
Ara wa ni bọbọ yẹn
Ara wa
O ya k'ẹnikẹni ma wo baby yẹn o
Ọmọ wa ni
Ọmọ wa ni baby yẹn
Ọmọ wa ni
A mọ 'ra wa o
A mọ 'ra wa o
Oh ohh
Awọn tiwa mọ'ra wa o
A mọ'ra wa o
A mọ 'ra wa o
A mọ 'ra wa o
Oh ohh
Awọn tiwa mọ'ra wa o
A mọ 'ra wa o
Written by: Oluwaseun Morihanfen